Home / Author Archives: admin (page 38)

Author Archives: admin

Inu fiimu wo ni aworan yii ti jade?

Read More »
fasola

Ofiisi Fasola tuntun: Ise minisita ti bere ni perewu

Minisita fun ise ode, mona-mona ati eto ilegbe ti bere ise lofiisi re tuntun lana ojo Aje, Monde.

Read More »
mercy

Yeepa! Mercy Aigbe di Sulia Ayetoro

Sulia kan, Mercy kan, Walahai Ayetoro kan ni

Read More »
arun oju

Arun oju: Ohun ti e o se ti oju ba n su tabi yun yin

Ti oju ba yun eniyan, tabi ti oju naa ba n su. Olayemi Oniroyin ti lo sewadii nipa ona ti eniyan fi le setoju iru oju bee lona to rorun ju lo. Ti eni naa yoo si bo ninu wahala ...

Read More »
olamide

“Eyan Mayweather” ni awo orin tuntun Olamide Ogbeni (Mr) . Baddo

Olamide, Ogbeni (Mr) Baddo ti kede ojo ti yo ju awo orin re tuntun sigboro aye. Awo orin tuntun to pe akole re ni “Eyan Mayweather” ni yoo maa dagboro ru, bere lati ojo ketalelogun osu kokanla odun yii (23/11/15). ...

Read More »
mercy

Mercy Aigbe alaso oge pade Toke Makinwa

Awon Yoruba bo, won ni tode-tode ni i se alaso tuntun. Joojumo ni Mercy n sodun, Mercy Aigbe alaso oge.  Mercy tun pade Toke, sorosoro ori redio ati telifisan ti oun naa feran oge lagbo ariya.

Read More »
Maheeda

Maheeda di Pasito oloro itunnu

Kosi eni ti Olorun ko le fi owo to lokan. Maheeda, okan ninu awon olorin ile Naijiria, ti ma n bora sile nihoho tele ti wa di eni ti n gba awon eniyan niyanju bayii pelu oro itunnu ti n ...

Read More »
dayo amusa

Dayo Amusa ti pada senu ise

Dayo Amusa wa lara awon ero Mecca odun yii pelu awon akegbe re bi Fathia Balogun ni won jo goke arafa papo. Igba ti won de ni won di Alaaja tuntun. Sugbon bayii, Dayo ti pade sidi ise oojo re nibi ...

Read More »

Donald Duke se afihan iwa omoluabi ati irele

Read More »

Eleleture lati owo Akeem Lasisi

  Eyi ni fidio orin ewi lati owo Akeem Lasisi ti won pe akole re ni ELELETURE

Read More »