This video explains, with sufficient examples, the meaning of the words ‘esu’ and ‘elegbara’. It tells Sis exactly who Esu is in the Yoruba pantheon of the orisa and also gives insight into the characters of the children called Idowu ...
Read More »Home / Author Archives: ayangalu (page 2)
Àwọ̀ ni Édè Yorùbá – Colours in Yoruba Language
Dúdú – BlackÀwọ̀ Ojú Ọ̀run – BlueÀwọ̀ igi – BrownÀwọ̀ Eérú – GrayÀwọ̀ Ewé – GreenÀwọ̀ Òféfèé – OrangePupa – RedFunfun – WhitePupa rusurusu – YellowÀwọ̀ dúdú – Dark colorLight color: Àwọ̀ tí ó mọ́lẹ̀Colors: Àwọn àwọ̀ Ojú Ọ̀run dúdú díẹ̀ – ...
Read More »Òwe Tòní
Ikán parapọ̀, ikán mọ ilé; èèrùn parapọ̀, wọ́n mọ àgìyàn; àwọn oyin parapọ̀, wọ́n mọ afárá. TranslationThrough collective labour, termites erected majestic cities, ants built fortified strongholds, and bees fashioned efficient honeycombs. WisdomUnity is strength, and together, we achieve more! ...
Read More »Òwe Tòní
Apọnkọ kéré ò gbọn to asọwò márà, ọgbọn asọwò márà kò tó ti ajéáwọgba, ọgbọn ajéáwọgba kò tó ti Ìyá mi ò ran mi lẹkọ̀. The person who sells a short measure of pap is not as smart as the ...
Read More »