Elegua or Ellegua comes from the word Elegbara which means spirit of the trickster. When the Atlantic slave trade took place, alot of the Oodua (Yoruba) words got corrupted mis-pronounced and mis-spelled because of the Spanish dialect.Gbara – strengthElegba – spirit ...
Read More »A ti gba 800 bílíọ̀nù owóòlú tí wọ́n jí kó, àwọn 1,400 ti dèrò ẹ̀wọ̀n– Lai Mohammed
A ti gba 800 bílíọ̀nù owóòlú tí wọ́n jí kó, àwọn 1,400 ti dèrò ẹ̀wọ̀n– Lai Mohammed Ẹdìyẹ ń làágùn, ìyẹ́ ni kò jẹ́ kó hàn.Ìjọba àpapọ̀ ti sọ pé òun ti gba owó tó lé ní ẹgbẹ̀rin bílíọ̀nù náírà ...
Read More »EID: Babalawo or Traditionalists Come and defend yourself if you are one of such character?
Babalawo or Traditionalists that attend EID or obey Islamic Rules are Con-Artist known as Professional Sacrilegious Fraudsters; and better still a Spiritual Criminal! Come and defend yourself if you are one such character?
Read More »Àwo̩n aronúpìwàda Boko Haram ké̩kò̩ó̩ parí
Ìjọba ṣetán láti ra irinṣẹ́, sanwó oṣù fún adúnkookò mọ́ni tẹ́lẹ̀ Àwọn ikọ̀ agbésùnmọ̀mí tó to mọkanlelẹgbẹta ti wọ́n jọ̀wọ́ ara wọn fún ìjọba, ti kẹ́kọ́ọ̀ jáde nílé ẹ̀kọ́ . Ìjọba sì ti setán láti má a san owó ìrànwọ́ ...
Read More »Fayemi kó àjàkálè̩ àrùn covid-19
Fayemi kó àjàkálè̩ àrùn covid-19 Gomina kayode Fayemi ti ipinle Ekiti to darapo pelu awon gomina to ko ajakale arun coronavirus.Fayemi kede eyi lori ero Twitter re pe saka ni ara oun da sugbon ayewo fihan pe arun naa wa ...
Read More »Oodua words for today
Today’s Oodua words
Read More »Video: Egungun festival
Ifá ní yini yini kí eni le se òmíràn
Adífáfún ifátérú tí se omokùnrin ìgódó,Èdùmàrè àwa yìn ó kí o tún le se òmírán.?????I give thanks to Elédùmarè, for everything he has done for me, orí modupe, Ifa modupe, Egbe aye ati t’òrun modupe lowo yin.?????? Thanks to everyone ...
Read More »APC kò ní ì ṣe ìdìbò ní ìpínlẹ̀ Òǹdó àyàfi.. Olùdíje kan
APC kò ní ì ṣe ìdìbò ní ìpínlẹ̀ Òǹdó àyàfi.. Olùdíje kan Láìpẹ́ yìí ni ìròyìn kàn pé ìgbìmọ̀ ẹgbẹ́ òṣèlú All Progressive Congress (APC) tó ń ṣe àyẹ̀wò àwọn olùdíje lábẹ́ ẹgbẹ́ náà sọ pé Segun Abraham ni kò ...
Read More »Wọ́n gbẹ̀mí olórí ẹgbẹ́ jàǹdùkú ”One Million Boys” n’Ìbàdàn
Wọ́n gbẹ̀mí olórí ẹgbẹ́ jàǹdùkú ”One Million Boys” n’Ìbàdàn Ọmọ ò fìgbàkan láyọ̀lé, ẹni ọmọ dúró sin onítọ̀ùn ló bímọ. Gbogbo ẹni tó bá bí jàǹdùkú, olè, gbàjùẹ, kọ̀lọ̀rànsí l’ọ́mọ, kónítọ̀ùn ó má tíì yọ̀ láyọ̀jù nítorí pé *ÀBÍKÚ ÀGBÀ* ...
Read More »