Ase!
Read More »Ẹgbẹ́ Àwọn Àgbààgbà Oòduà Ní Osinbajo Kò Gbọdọ̀ Kọ̀wé Fipò Ẹ̀ Sílẹ̀
http://iroyinowuro.com.ng/2019/11/09/egbe-awon-agbaagba-yoruba-ni-osinbajo-ko-gbodo-kowe-fipo-e-sile/ Ẹgbẹ́ àwọn àgbààgbà Oòduà (Yorùbá) ní Osinbajo kò gbọdọ̀ kọ̀wé fipò ẹ̀ sílẹ̀ Fẹ́mi Akínṣọlá Èyí ò tófò, kò tófò,fìlà aráabí kù rébété, Kemi Adeoṣun lọ , orí ló kó Adebayọ Shittu yọ,tó fi rí sáa àkọ́kọ́ lò já.Ní ...
Read More »Ìjọ Kátólíkì Bẹ̀rẹ̀ Ìwáàdì Lẹ̀yìn Tí Àwọn Sisitá Méjì Lóyún Ójijì
http://iroyinowuro.com.ng/2019/11/09/ijo-katoliki-bere-iwaadi-leyin-ti-awon-sisita-meji-loyun-ojiji/ Ìjọ Kátólíkì bẹ̀rẹ̀ ìwáàdì lẹ̀yìn tí àwọn sisitá méjì lóyún ójijì Fẹ́mi Akínṣọlá Eemọ̀ lukutu pẹ́bẹ́,kò síbi tí ìṣe ò sí. Ayé dojú kejì, wọ́n ń bámí ẹran níhòòdí ọmọ èèyàn. Ìjọ Kátólíìkì ti ń ṣe ìwádìí bí àwọn ...
Read More »Singer #SoundSultan Declares Ede Oodua (Yoruba) As The official Language In His House.
Singer SoundSultan reveals why he declared Ede Oodua (Yoruba Oodua Language) as the official language in his house . The Oduduwa super star shared the picture above on his IG profile and captioned it with “I JUST REALISED WHILE I WAS FULFILLING THIS BIG ...
Read More »Seyi Makinde ṣe àbẹ̀wò sí ibùdó ìtọ́jú èèyàn 200 tí ọlọ́pàá tú sílẹ̀ ní ilé Ọlọ́rẹ
Seyi Makinde ṣe àbẹ̀wò sí ibùdó ìtọ́jú èèyàn 200 tí ọlọ́pàá tú sílẹ̀ ní ilé Ọlọ́rẹ Fẹ́mi Akínṣọlá Gómìnà ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́Seyi Makinde ti se àbẹ̀wò sí ilé Ọlọrẹ tó wà ní àdúgbò Ọ̀jọ́ nílùú Ibadan .Bẹ́ẹ̀ bá gbàgbé, ilé yìí ...
Read More »N kò leè fi ìdúnú mi pamọ́ lọ́jọ́ ìkómọ àwọn ìbẹta….Yinka Ayefele
N kò leè fi ìdúnú mi pamọ́ lọ́jọ́ ìkómọ àwọn ìbẹta….Yinka Ayefele Fẹ́mi Akínṣọlá Ẹ̀dá ò láròpin láyé, ṣé bí ó se wu Olúwa Ọba níí sọlá, fẹ́ni Ó wù ú,bẹ́ẹ̀ gẹ́lẹ́ ni ọ̀rọ̀ níbi tí t’ọba, tìjòyè, ọ̀tọ̀kùlú ìlú ...
Read More »Èmi ò kì ń s̩e “His Excellency” – Sanwo-olu
Ogbeni Babajide Sanwo-olu ni mi. Mi o ki n n se “His excellency”.Gomina ipinle Eko lo n salaye yii fun awon oniroyin lonii ojo kefa osu kokanla odun yii.Gomina ni igberaga wa ninu oruko ” His Excellency “. E saa ...
Read More »Feliz Ojo’se Òòsà.
Ẹ̀là mo yìn bọrú.Ẹ̀là mo yìn bọyè.Ẹ̀là mo yìn bọ’ṣíṣẹ. Feliz Ojo’se Òòsà. Òlódumarè les bendiga y que la luz de Obàtálá ilumine sus vidas, hoy en este día de veneracion a los Òrìsàs funfun y a nuestro linaje ancestral ...
Read More »A Dúró Lójú Òpó Ìdájọ́ Ilé Ẹjọ́ Àkọ́kọ́ Lórí Ẹjọ́ Ajimobi – Adájọ́
A dúró lójú òpó ìdájọ́ ilé Ẹjọ́ àkọ́kọ́ lórí ẹjọ́ Ajimobi – Adájọ́ Fẹ́mi Akínṣọlá Gómìnà àná ní Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ Abiola Ajimọbi ti fìdí rẹmi nínú ìpẹ̀jọ́ rẹ̀ láti tako ìbò tí ó gbé ojúgbà rẹ̀ Kọla Balogun wọlé gẹ́gẹ́ ...
Read More »Àṣírí Pásìtọ̀ Tó Ń Fí Sọ́ọ̀si Ṣe Ọ̀gbà Wèrè Tú
Àṣírí pásìtọ̀ tó ń fí sọ́ọ̀si ṣe ọ̀gbà wèrè tú Fẹ́mi Akínṣọlá Ṣé biribiri òkuǹkùn ọ̀rọ̀ lójú ọmọ aádámọ̀ ,ìmọ̀lẹ̀ gbòò ni lójú Adẹ́dàá. Ní báyìí, Olùsọ́ àgùtàn Joseph Ojo, ní ọwọ ṣìnkún ọlọpàá ti mú fún lílo ilé ìjọsìn ...
Read More »