All candidates seeking admission into all tertiary institutions in Lagos State must henceforth possess credit in Yoruba Language, the state Yoruba Language Preservation and Preservation Law has said. . According to ThisDay, the law, which became effective last Thursday, would ...
Read More »Iwulo Ati Anfaani Ti Orí Nse Ninu Igbesi Ayé Omo Eda Eniyan
Ekaaro eyin eniyan mi, aku ise ana o, a sin tun ku imura toni, mose ni iwure laaro yi wipe Eledumare ninu aanu re koni jeki ire oni yi fiwa sile Àse. Idanileko mi toni da lori orí wa, opolopo ...
Read More »Opepe aye Ifa dun opepe !
Please sing along with me as follows :- Opepe aye Ifa dun opepe Nijo eku eleku Opepe, eleku o gbodo rojo opepe Nijo eja eleja Opepe, eleja o gbodo sunkun Opepe Nijo eye eleye Opepe, eleye o gbodo rojo opepe ...
Read More »OGUN: Deity of War!
Iron (metallic) materials (in general) Palm frond (Mariwo Ope), dog, tortoise, roasted yam, red palm-oil, cock, Palm wine were the favor objects of Nature in use by the Deity of Ogun when on earth. Hence, Ogun propitiators revere the use ...
Read More »Odu Eji Ogbe – The Chant
Ori koo da mi ‘re – Ori bless me abundantly Orisa ma jee nsowo asenu – Orisa do not let me labor in vain Adifa fun okankan lenirunwo Irunmole – Divinated for 401 + 1 Orisa Nigbati won ntode orun ...
Read More »There is Mathematics, Philosophy, religion others in Ifa
Watch the Mathematics of IFÁ part 2 by Tundé ADÉGBỌLÁ
Read More »Èsù Óólogbè!
Ekaaro eyin eniyan mi, aojiire bi? Aku ise ana o, bi a se njade lo loni Eledumare ninu aanu re yio jeki ire oni yi je tiwa Àse. Laaro yi mofe soro soki nipa èsù òdàrà, o seni laanu lode ...
Read More »Owó✋lá fi n sisé owó
Esè la fí ñ rìnnà Olà Àtowó àtesè ki Elédùmarè má gba ìkankan nínú rè lówó wa, ká lè fi rí nñkan Ajé kó jo… Asáré pajé Arìngbèrè polà Òhun ewà ní wón jó n wòlú Adífáfún Ògbìngbìn kan Ògbìngbìn ...
Read More »Quote of the Century: Esu is infinite love, and very patient
“If Esu were bad, and not infinitely patient he would have wrecked vengeance on all those religious charlatans who malign him on a daily basis. He is such a gentle, forgiving soul, and keeps quiet, knowing that the hour is ...
Read More »