Àrídájú ti so wípé… 1. Àwon ènìyàn kan wà tí won ń lo orúko àti ipò Aláàfin láti fi lu àwon tí kò mò nípa Àsà yorùba ní jìbìtì ní ìlú òyìnbó. 2. Àwon babaláwo tí ó wà lábé ilé-ifá ...
Read More »Fatai Owoseni sàkóso lílo bíbò ní Ikorodu láti owó omo oòduà rere !
Kàyééfi ńlá gbáà ni súnkere fàkere okò tí ó selè ní ìròlé àná ní bóòsì dúró Agric (Agric bus stop), Ikorodu ní ìlú Èkó. Tí ó kan ògá pátápátá ilé-isé olóòpá (commissioner of police) Ògbéni Fatai Owoseni láti yo òpòlopò ...
Read More »Bómbù Déru Bà Wón Ní Ilé-ìfowópamó Diamond (Diamond Bank) Ní Ìlú Jos
Bómbù déru bà wón ní ilé-ìfowópamó Diamond (Diamond bank) ní ìlú Jos, Bí won se fura wípé wón ti wà okò kan gúnlè tí irinsé olóró Bómbù sì wà ní inú rè. Gbogbo òsìsé ilé-ìfowópamó Diamond ti eka Katako, ní ...
Read More »Àwòrán Kí Ó Tó Di Ojó Ìgbeyàwó Láàrin Eléyàmeyà
Omo Ooduarere tún gbé tuntun dé ooo, àwòrán kí ó tó di ojó ìgbeyàwó láàrin eléyàmeyà. Femi (yorùba) àti Mma rè tí ó ń jé OGECHI láti (River), inú won dùn púpò gan bí won se ya àwòrán papò nínu aso ...
Read More »Do you know why Ose Ifa is very important? (Must Read)
Let me tell you the super story given to me by my father, Oloye Akano Fasina Agboola, late Araba of Lagos. This is repeated for those who have never heard it before. A Babalawo whose nickname is “Ifa a je ...
Read More »Bitter truth must be said no matter who is affected!
Why couldn’t these pastors, evangelists, bishops, alagbas, deacons, deaconesses, apostles, alfas, imams etc identify the armed robbers, kidnappers, National Treasury looters, 419 specialists, yahoo yahoo fraudsters etc who come to their churches and mosques with big money but can ...
Read More »Review: OIori – Latest Yoruba Movie 2017 (Propaganda, Fraud, Scam & Pure Blaspheme against Isese)
Blashpeme The Fiction film above (OIori – Latest Yoruba Movie 2017) is an example of how a direct attack, fraud, misinformation/information war and scam has went on against the Yoruba civilization (Isese) for over a century. Out of all the ...
Read More »Iná gbé arabìnrin kan tí ó jé akékòó ifáfitì ní ìjoba ìpínlè River (River state university).
Akékòó ifáfitì ní Ìjoba ìpínlè River kan tí a ò tíì mo eye to ó su ú ni Iná gbé ní ojó ìségun (Tuesday) ojó ketàlá osù kefà (June 13). A bá a tí ó subú lulè léègbé kan tí ...
Read More »Tonto Dikeh Pèlú Muhammed Lai Nínú Okò Ojú Òfurunfú
Gbajúgbajà òsèré Tonto Dikeh àti Asàkóso ìwí àti Àsà (minister of information and culture) Muhammed Lai. Ya àwòrán nínu okò ojú òfurunfú nínu ipò tí ó wà ní ìsàlè. “mo wo bí ayò mi se kún tó nígba tí Hon. ...
Read More »Ewi Toni: Toju Iwa Re Ore Mi
Toju iwa re, ore mi; Ola a ma si lo n’ile eni, Ewa a si ma si l’ara enia, Olowo oni ‘nd’olosi b’o d’ola. Okun l’ola; okun n’igbi oro, Gbogbo won l’o nsi lo n’ile eni; Sugbon iwa ni m’ba ...
Read More »