Àwon òdó se ayeye ojó ìbí fún Ààre télè, Goodluck Ebele Jonathan ní ìgbà tí ó pé omo ogóta odún (60th).
Ogúnl’ógbòn àwon òdó ni won péjú níbi ayeye ojó ìbí Ààre orílè èdè Nàíjíríà télè, Goodluck Ebele Jonathan láti ba se ayeye ojó ìbí rè nígbà tí ó pé omo ogota odún. E wo àwòrán n’ísàlè .
Read More »
Ọmọ Oòduà Naija Gist | News From Nigeria | Entertainment gist Nigeria|Networking|News.. Visit for Nigeria breaking news , Nigerian Movies , Naija music , Jobs In Nigeria , Naija News , Nollywood, Gist and more











