| | | | | | | | | | | Ekaaro eyin eniyan mi, aojiire bi? Aku ise ana o, gegebi oni se je ojo isegun olorun alagbara yio muwa bori Ogun ota ase. Odu ifa IROSUN OPINNI/ ...
Read More »
Àṣà Oòduà, Asa Ibile Oòduà. Oòduà (Yoruba) je okan ninu awon eya ti o laju ju lode aye yi. Lati igba ti alaye ti daye ni won ti ni eto ati ilana to kun nipa ohun gbogbo ti won nse ni igbesi ayee won.
ayangalu Comments Off on Odu ifa IROSUN OPINNI/ IROSUN ORO
| | | | | | | | | | | Ekaaro eyin eniyan mi, aojiire bi? Aku ise ana o, gegebi oni se je ojo isegun olorun alagbara yio muwa bori Ogun ota ase. Odu ifa IROSUN OPINNI/ ...
Read More »*Aje ko ni di ota a mi. *Edumare dakun fidi aje sole nile mi. *Imo ota, imo elenini ko ni se lori mi. *Emi ko ni di eni arisa ati arisunkun. *Edumare fi aso iyi wo mi(Ase). Aare Olasunkanmi Alani ...
Read More »ayangalu Comments Off on Ore yeye Osun!
May we all be blessed today and beyond. Ore yeye Osun! Take it to the river. Ore yeye Osun! – – –
Read More »ayangalu Comments Off on Iyawo tagbe wani ojo aiku mati soro, egbo bose wi
Olotu: ekasan ooo eyin ara ile,asiku asiko yin, eledua yowa pelu gbogbo wa o,ase. Iyawo tagbe wani ojo aiku mati soro egbo bose wic….Gbogbo eyin ebi mofe ki e fi ise yin bura fun mi pe ti moba so e ...
Read More »ayangalu Comments Off on Alaso funfun
Cc- Yèyé Èkìtì
Read More »ayangalu Comments Off on Odu ifa IROSUN ATAPO – Faniyi David Osagbami
| | | | | | | | | | | Ekaaro eyin eniyan mi, aojiire bi? Aku ise ana o, bi a se njade lo laaro yi pelu ayo ati alaafia a koni pada sile pelu ...
Read More »ayangalu Comments Off on Iba Bambi Oluorojo arigba ota segun!
Arira mase fi ina re na mi o! Aase! A ku Ose Sango! Cc- IyaOgbe OmoEdu Yeyelufe Oyewole
Read More »ayangalu Comments Off on Abi e roju aye bi?
Orewa nso fun ara ile wipe ki won Ba oun gbe orin, sugbon won o da loun, lo ba binu lo Si oko o da orin sugbon won o fun lounje, o tun lo si Odo o da orin won ...
Read More »ayangalu Comments Off on Ounje emi fun t’ooro yii ( 20 – 07 – 2016 )
HUN !!! # Odo to gbagbe # Orisun … Gbigbe nii gbe … WOO ORE WA !!! Ibi Ipile eda L’orisun won.. Ibi Eniyan ti lalehu ni Ipile re… Eni to bini Orisun eni nii se… Eniyan to wo’ni dagba ...
Read More »ayangalu Comments Off on Iyawo: mi o le gba ki iya oko mi gbe pelu mi lailai.
Olotu:kini ikan tori tofi ni o le gba ki iya gbe pelu re,gbogbo awon eyan loti ba e so,o ko,o loni gbo,won tun gbe e wa sori afefe,agidi yi nan lotun lo.Kini ikan to sele gan. Iyawo:seri olotu,mole gba ki ...
Read More »
Ọmọ Oòduà Naija Gist | News From Nigeria | Entertainment gist Nigeria|Networking|News.. Visit for Nigeria breaking news , Nigerian Movies , Naija music , Jobs In Nigeria , Naija News , Nollywood, Gist and more