Ojumo ti mo Eda ti ji saye Eda ti ko mose asela Ka ji ni kutu hai Ka gbegba pota Iya Akanke nko O ti re werenjeje Baba Talabi da O ti sare re kutuwenji Ki ni n le wa? ...
Read More »
Àṣà Oòduà, Asa Ibile Oòduà. Oòduà (Yoruba) je okan ninu awon eya ti o laju ju lode aye yi. Lati igba ti alaye ti daye ni won ti ni eto ati ilana to kun nipa ohun gbogbo ti won nse ni igbesi ayee won.
ayangalu Comments Off on Ewi Toni – 20.03.2016
Ojumo ti mo Eda ti ji saye Eda ti ko mose asela Ka ji ni kutu hai Ka gbegba pota Iya Akanke nko O ti re werenjeje Baba Talabi da O ti sare re kutuwenji Ki ni n le wa? ...
Read More »admin Comments Off on #Gbagede Asa-19/03/2016
Omo Oduduwa, Olodumare jogun awo to rewa fun wa; awo dudu ni gbogbo aye mo iran wa si, bo sie je wipe alawo pupa die naa nbe ninu-un wa. ……. Ewa n be lara awo dudu, nitori awa gan ni ...
Read More »admin Comments Off on Ewi Toni: Atoto arere
Gbogbo omo Yoruba Ki gbogbo eye igbo pa lolo Etu to n numo lowo O ma lee numo Gbogbo Ekulu ko ma lee numo loka Omo Ade ti de to fe korin ogbon Akewi Imoran de to fe farofo sasaro ...
Read More »admin Comments Off on Laye Atijo: Opo Sisu (Nje o dara lati maa supo?)
Ni akoko, mo sure fun toko-taya pe iku aitojo ko ni pa gbogbo wa o(ASE EDUMARE). …….. Ni aye atijo, ti oko ba tete ku, ti iyawo re si tun wa loju-opon, won o ba so pe ki aburo oko ...
Read More »admin Comments Off on Iwure Owuro – 18/03/2016
E MAA WI TELE MI : …… *Sekere kii rode ibanuje, oro ibanuje koni je temi. *Tijo-tayo ni ti sekere, oro ayo ati idunnu ko ni tan ninu ile mi. *Ogun idile ko ni bori mi. *Ki osu yii to ...
Read More »admin Comments Off on Emi Ibinu
Oruko mi ni IBINU, emi ko le fun wara, sugbon mo le da wara nu. Ise ti eniyan ba fi ogun odun ko jo, emi IBINU le fi iseju kan baaje. Sora fun emi IBINU ti o ba fe se ...
Read More »admin Comments Off on Regina Chukwu lori eto Gbajumo Osere
admin Comments Off on Taiwo Ibikunle lori eto Gbajumo Osere
admin Comments Off on Koffi lori eto Gbajumo Osere
admin Comments Off on Tayo Adeleye lori eto Gbajumo Osere
Ọmọ Oòduà Naija Gist | News From Nigeria | Entertainment gist Nigeria|Networking|News.. Visit for Nigeria breaking news , Nigerian Movies , Naija music , Jobs In Nigeria , Naija News , Nollywood, Gist and more