Irawo oserebirin, Mercy Aigbe aya Lanre Gentry, ni won ka mo odo iya alagbado nibi ti omobirin naa ti n ra langbe je. Oserebirin to kawe gbogbo ninu Ere Onise ti a mo si Theatre Art ni Ifafiti ijoba apapo ...
Read More »Aja Je Omo Tuntun Niluu Asaba !
Abiyamo Padanu Omo Re Kan Soso Sinu Agbara Eje Isele kan to sele lojo Eti to koja yii ni Asaba to wa ni Ipinle Delta je eyi to ba ni lokan je jina. Arabirin kan, eni odun metadinlogoji (37), Maureen ...
Read More »Awon foto: Ayeye Igbeyawo Omo Gomina Abiola Ajimobi Le Ku!
Oni ojo kokanlelogun, osu kejo (Aug 21), odun 2015 ni Gomina Abiola Ajimobi n se igbeyawo fun omo re obirin, Ajibola pelu oko omo re, Ayokunle Olayiwola. Orisirisi awon eniyan nlanla ati awon gomina lati apa iwo-oorun guusu Naijeria ni ...
Read More »Eledumare ki odun yi to pari kole temi fun mi….iwo nko ?
Ase !
Read More »oruko wo ni iwo mo eranko yisi
Ogundameji: IFA verse for physical & spiritual protection against enemies
Ogundameji is the IFA verse to be recites every day by any person who want to be protected from physical and any spiritual attack.recite this every day. A Mon anan A Mon oni A aa mola Botunla omo iya e ...
Read More »Iba akodaaa: Mojuba o !!
iba akodaaa, iba ase daa, iba eyin atun nida, iba eyin alagbara oru, iba eyin alagbara aro, iba eyin t’eledua tun gbe agbara osan le lowo, iba yin o. ORUNMILA iba re, olu ifa, ade ifa, . . .Mojuba o, ...
Read More »Won ni Ki O Mu Eyo Kan peere E wo le ma Mu ?
Yoruba: How Top 3 Nigeria’s traditional rulers are selected (Yoruba)
Yoruba In Yoruba tradition, even though the position is hereditary, there are three to four families that are entitled to the throne. It is like a rotational system of government where rulership of a kingdom is circulated among the different ...
Read More »Bi odun yi se n pari lo a ko ni ri ogun ewon !
lase Edumare
Read More »