Oni ki awon omo ijo Bora won si Ihoho ki oun tole gba adura fun ti awaon oponu omo ijo si bora won si Ihoho ni ita Gbangba, Ibere timo fe bere lowo awaon elesin cristeni ni pe se ara ...
Read More »
Àṣà Oòduà, Asa Ibile Oòduà. Oòduà (Yoruba) je okan ninu awon eya ti o laju ju lode aye yi. Lati igba ti alaye ti daye ni won ti ni eto ati ilana to kun nipa ohun gbogbo ti won nse ni igbesi ayee won.
admin Comments Off on Lobatan: Se pasto ni kape Eleyi ni abi satani (Satan) ninu bibeli ?
Oni ki awon omo ijo Bora won si Ihoho ki oun tole gba adura fun ti awaon oponu omo ijo si bora won si Ihoho ni ita Gbangba, Ibere timo fe bere lowo awaon elesin cristeni ni pe se ara ...
Read More »Edakun, tani mo Oruko ti won pe Kokoro yi ?
Read More »admin Comments Off on Moki gbogbowa wipe aku ewu osu titun ti o wọle de wẹrẹ waba waa !
Mogbaladura wipe ogun aṣeti koni je tiwa ninu osu na,eni na tuni ọjọ (ẹtì) ti wonpeni (friday)…olodumare koni je ki akoju ogun aṣeti nile aye emi ati iwọ… Ẹni tikole tele,ẹniti wa ọmọ latibi,ẹni fe aṣerori lori adawole ẹ,ẹni todawọ ...
Read More »admin Comments Off on Otito lawo aiye, iro lagbele ro !
Owonrin omo ase’ka bi eni ti soo’to, Otito ba le di odo, ika bale di yangi, difa fun owonrin lojo tofe lo ya apo ika, E je kase otito, ka ya apo ika danu, Oore lope, ika koye omo Eniyan- ...
Read More »admin Comments Off on Oro kan se le si ore mi sugbon ko ye mi o!
O gba obinrin kan si le sugbon obinrin yi gbe omo lowo sugbon bi ki ore mi ofe lo se obinrin yi le yin osun meji oro won ti wo de bi pe bi won ba ti ri ara won ...
Read More »Yoo’ba loma n sope Igbin koni da enu dele koma jifa ile Ifa owo ifa omo Ifa Alafia Ifa Ire Gbogbo kio wole to emin ati Iwo wa ! Ase !
Read More »admin Comments Off on Ewo lo lagbara ju ninu gbolohun wonyi lagbo ife ?
Moki gbogbo ile, e gbo ewo lo lagbara ju ninu gbolohun wonyi lagbo ife ? 1, o ti pari laarin emin ati iwo 2,odabo 3, min o ni ife re 4, mo ti un fe elomiran 5, ma pe ero ...
Read More »admin Comments Off on E fura ooo!!
Eyi ni lati sofun yin wipe anwa arakunrin kan ti oruko re nje Mukaila,ti o je onisowo eran maalu ni onibuore ni agbegbe iyana church ni ilu Ibadan. Arakunrin yi ni awon kan pe lati ori ero ilewo re lati ...
Read More »admin Comments Off on Oruko Kan fun Arakunrin ?
Ọmọ Oòduà Naija Gist | News From Nigeria | Entertainment gist Nigeria|Networking|News.. Visit for Nigeria breaking news , Nigerian Movies , Naija music , Jobs In Nigeria , Naija News , Nollywood, Gist and more