Home / Art / Àṣà Oòduà (page 164)

Àṣà Oòduà

Àṣà Oòduà, Asa Ibile Oòduà. Oòduà (Yoruba) je okan ninu awon eya ti o laju ju lode aye yi. Lati igba ti alaye ti daye ni won ti ni eto ati ilana to kun nipa ohun gbogbo ti won nse ni igbesi ayee won.

Gbolohun kan fun ogbeni yii ?

E’dakun n je a leri Gbolohun kan fun ogbeni yii ?

Read More »

Arakunrin yi se ijoba fun odun mefa !

N je o ye ki o tun so wipe o n tun fe se odun merin miran ati wipe se o ye ki yoruba se ati leyin fun

Read More »

Oruko kan fun ogbeni yii ?

E wa fun ogbeni yii ni  Oruko kan ?

Read More »

Ni oni tise ọjọ aje emi ati iwọ amari tiaje se !

Aje rere awole tọ ẹni kankan wa wáa….owo ayọ ni ama pajale ose..a oni pawo ẹjọ,wahala,isan,ibanuje .owo ayọ ni mapa…igi aje amaso nile oluka lukuwa…ase…ifakanso ni odu e bayi wipe…… Arakoko ki adifa fun wọn nilu ọwọlọ eyiti igi aje ...

Read More »
Sweet potatoes

Oruko wo ni eyin npe ounje yi ni adugbo tiyin ?

Se won le fi gun iyan ?

Read More »

Ohun tama je lanwa kama pade n’toma jewa. Gbiyan ju lati se Ase !

Ase !!

Read More »

Anu opolopo obinrin si se mi lojo oni !

Hunmmmmmm, Ẹ ku ọsan o, e ku ataaro o, o ga o, anu opolopo obinrin si se mi lojo oni, nitori opolopo ninu won lo ti so aponle ara re nu niti tori eja #300 ati hi malt #100, tabi tori ...

Read More »

Tan fe ku kosi lojo idibo emi pelu obe lajo nlo dibo ,loxxxxxx

E dakun ,oruko wo loda fun mama ?

Read More »

Talo mo oruko, ogbontarigi okunrin ogun yi?

E jo kini oruko, ogbontarigi okunrin ogun yi?

Read More »

Oruko wo ni iwo mo ohun to wa loju aworan yii si?

Read More »

Viral Video

Support Ooduarere

SUPPORT OODUARERE
Scan QR code below to Donate Bitcoin to Ooduarere
Bitcoin address:
1FN2hvx5tGG7PisyzzDoypdX37TeWa9uwb