Home / Art / Àṣà Oòduà (page 167)

Àṣà Oòduà

Àṣà Oòduà, Asa Ibile Oòduà. Oòduà (Yoruba) je okan ninu awon eya ti o laju ju lode aye yi. Lati igba ti alaye ti daye ni won ti ni eto ati ilana to kun nipa ohun gbogbo ti won nse ni igbesi ayee won.

IWURE ODUN TUNTUN 2015

IWURE ODUN TUNTUN A si ku odun, a ku iyedun. Olodun a wo omo fun wa. Kewekewe koni ko wa l’omo lo. Aseye ni alakan ns’epo ti e Aseye ni tiwa o. Aseti, akoti koni kan wa T’oko, t’aya ati ...

Read More »

Ẹ̀ta Òkò

Read More »

OOOOOREyeyeoooooGBEMI ninuODUNyiOOOOO!

Ase !!

Read More »
ifa

IFA NI KASOPE, KASOPE

IFA NI KASOPE, KASOPE MO NI KASOPE KASOPE IFA NI KOMO EKU O SOPE OMO EKU LOHUN LOPE DA IYAN LOMO ARAYE NFI OMO EKU JE IFA NI KASOPE KASOPE MO NI KASOPE KASOPE IFA NI KOMO ERAN O SOPE ...

Read More »

Opon Ifa !

Read More »

Gbolohun kan fun Arakunrin ti Adire’re nsalo nijo Keresimesi

Read More »

ORI……ori yeye nii mo GUN……

Ase Oriwa konibabode…..Ogbo Ato lankira ni’ledi……Ogun Lakaaye adowo fomo Awo

Read More »

Kinni yato laarin olodumare ati Eledumare?

E gbo kinni yato laarin oloodumare ati  Eledumare?

Read More »

Aalo apamo – Mayaki Ojo

Aalo apamo Obi awe kan aje de oyo, baba kukuru de fila bentigo, kini nboba jeun ti kii mu sibi dani? Aguntan baba mi kan lailai, aguntan baba mi kan lailai, owoo ni nje kii je agbado. ( Ahon, oko, ...

Read More »

Bawo ni ipolowo oja oyinbo

Read More »

Viral Video

Support Ooduarere

SUPPORT OODUARERE
Scan QR code below to Donate Bitcoin to Ooduarere
Bitcoin address:
1FN2hvx5tGG7PisyzzDoypdX37TeWa9uwb