Home / Art / Àṣà Oòduà (page 5)

Àṣà Oòduà

Àṣà Oòduà, Asa Ibile Oòduà. Oòduà (Yoruba) je okan ninu awon eya ti o laju ju lode aye yi. Lati igba ti alaye ti daye ni won ti ni eto ati ilana to kun nipa ohun gbogbo ti won nse ni igbesi ayee won.

UNILAG

Wọ́n ti yan adarí tuntun fún Ifásitì “Unilag”

Ó jọ bíi ẹni pé kángun kàngùn kángun ilé ẹ̀kọ́ Ifásitì ìpínlẹ̀ Èkó tí kángun síbi kan báyìí o, bí Ìròyìn tó ń tẹ̀ wá lọ́wọ́ ṣe ń fìdí rẹ̀ múlẹ̀ pé àwọn aláṣẹ Ilé ẹ̀kọ́ gíga Ifásitì Èkó, Unilag ...

Read More »
nigerian police

Sunday Shodipe tí wà láhàámọ wa– Alukoro ọlọ́pàá Ọ̀yọ́

Sunday Shodipe tí wà láhàámọ wa– Alukoro ọlọ́pàá Ọ̀yọ́ Fẹ́mi Akínṣọlá Ilé iṣẹ́ Ọlọ́pàá ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ ti sọ ọ̀rọ̀ kanranjágbọ́n afurasí Sunday Shodipe di ẹgbẹ̀rún ìsáǹsá tí wọn ò lè sá mọ́ Ọlọ́run lọ́wọ́, bí ìròyìn tó ń tẹ̀wà lọ́wọ́ ...

Read More »
olopa

A ti mú afurasí tó ń jẹ igbẹ níbàdàn–Ilé iṣẹ́ Ọlọ́pàá

A ti mú afurasí tó ń jẹ igbẹ níbàdàn–Ilé iṣẹ́ Ọlọ́pàá Ayé ń lọ sópin, ohun tétí ò fẹ́ ẹ̀ gbọ́ rí lojú ń rí báyìí o.Ilé iṣẹ́ ọlọ́pàá ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ ní ìwádìí ti bẹ̀rẹ̀ ní pẹrẹwu lóri ọkùnrin kan ...

Read More »
Bishop David Oyedepo

Bishop Oyedepo ní láti tẹ̀lé òfin tàbí kí ó dá orílèèdè tirẹ̀ sílẹ̀ – Iléesẹ́ Ààrẹ

Oludasile ile ijosinLiving Faith Church Worldwide, Bishop David Oyedepo lo ti n gbe peregi kana pelu ijoba apapo lati bii odun meloo kan seyin. Ofin lori owo ori ati amojuto awon ile-ise ati awon ile-ijosin ti ajo Company and Allied ...

Read More »

Iyawo Oloju Buluu

‘Kìí ṣe tìtorí owó ni mo ṣe fẹ́ gba Risikat padá, mo ní ìfẹ́ ẹ rẹ̀ ni ‘ Wasiu Jimoh, ọkọ Risikat tó ní ojú búlúù ní Ilọrin bá BBC Yorùbá sọ̀rọ̀, ìyàwó rẹ̀ náà fèsì. Iyawo Oloju Buluu Ẹ ...

Read More »
nigerian police

Họ́wù! Àgọ́ ọlọ́pàá ni wọ́n tí fọmọ odó lu èèyàn méjì pa

Họ́wù! Àgọ́ ọlọ́pàá n wọ́n tí fọmọ odó lu èèyàn méjì pa Ará kò níí tán nílé alárà láé láé. À bí kínni kí á tí wí pẹ̀lú bí èèyàn méjì ti kú lẹ́yìn tí ọlọ́pàá kan fi ọmọ odó ...

Read More »
eleye ika

Ẹlẹ́buùbọn gba ìpàdé àwọn ẹlẹyẹ ẹ̀ka ti Ọ̀ṣun

Ẹlẹ́buùbọn gba ìpàdé àwọn ẹlẹyẹ ẹ̀ka ti Ọ̀ṣun Fẹ́mi Akínṣọlá Gbajúgbajà onímọ̀ nípa ìṣègùn ìbílẹ̀ nílẹ̀ ẹ Yorùbá, tó tún jẹ́ Olóyè Àràbà nípìńlẹ̀ Oṣun. Ifáyemí Ẹlẹ́buùbọn ti gba ìpàdé ńlá àjọ̀dún ayẹyẹ àpapọ̀ ẹgbẹ́ àwọn oṣó àti àjẹ́ ní ...

Read More »
ẹgbẹ́ òṣèlú APC

Èàkàn ẹgbẹ́ òṣèlú APC mií Lanre Rasak dágbére fáyé

Èàkàn ẹgbẹ́ òṣèlú APC mií Lanre Rasak dágbére fáyé Èèkàn ẹgbẹ́ òṣèlú APC nípìńlẹ̀ Èkó, Lanre Razak ti jáde láyé lẹ́ni ọdún mẹ́rìnléláàdọ́rin. Kí ikú ó pajú èèyàn dé lójijì ti wá fẹ́ ẹ̀ kúrò ní ń tí wọ́n kíìyàn ...

Read More »
babatunde oke

Covid-19- kó̩ ló pa Babatunde Oke

Covid-19 ko lo pa Babatunde OkeOwuro oni ni won kede iku Alaga ijoba ibile Onigbongbo, Ogbeni Babatunde Oke. Gbogbo iroyin to gbee ni ajakale arun coronavirus lo paa. Won ni baba naa se aisan ranpe ni nnkan bii ose meta ...

Read More »

Sáká lára dá,Bàbá Ọbásanjọ́ kò l’árùn Kofi-19

Sáká lára dá,Bàbá Ọbásanjọ́ kò l’árùn Kofi-19 Fẹ́mi Akínṣọlá Agbẹnusọ fún Bàbá Ọbásanjọ́, Kehinde Akinyemi ló fi léde bẹ́ẹ̀ nínú àtẹjáde ní Ọjọ́ Ìsinmi pé àyẹ̀wò fihàn pé kò ní àrùn Kòrónáfairọ̀ọ̀sì. Akinyemi ní Ọjọ́ Keje, Oṣù Kẹjọ, ọdún 2020 ...

Read More »

Viral Video

Support Ooduarere

SUPPORT OODUARERE
Scan QR code below to Donate Bitcoin to Ooduarere
Bitcoin address:
1FN2hvx5tGG7PisyzzDoypdX37TeWa9uwb