Ọjọ́ Kẹrin oṣu Kẹ́jọ ni ìdánwò WAEC yóò bẹ̀rẹ̀ – Mínísítà ètò ẹ̀kọ́ Ìjọba àpapọ̀ ti kéde pé ìdánwò àṣeparí ní iléèwé girama, WAEC, yóó bẹ̀rẹ̀ lọ́jọ́ kẹrin oṣù Kẹjọ ọdúnMínísítà ètò ẹ̀kọ́, Emeka Nwajiuba ló fi ọ̀rọ̀ náà léde ...
Read More »Ebenezer Obey ò kú o–Asojú ẹgbẹ́ Obey
Ebenezer Obey ò kú o–Asojú ẹgbẹ́ Obey Ó dà bí ẹni pé àwọn èèyàn kìí fẹ́ rán aṣọ wọn níbi tó gbé ya mọ́ lóde òní. Ìtọ pinpin àti àríwísí ọ̀rọ̀ ọlọ́rọ̀ ló kù tí wọ́n ń mójútó, bọ̀kílẹ̀ èyí ...
Read More »Atiku, Saraki, Dogara ati Melaye lè má bó̩ nínú e̩jó̩ jìbìtì Hushpuppi- APC
Atiku, Saraki, Dogara ati Melaye lè má bó̩ nínú e̩jó̩ jìbìtì Hushpuppi- APC Ogbeni Ramoni Igbalode Abbas to je omo Naijiria ti owo te ni ilu Dubai pelu esun jibiti lilu lori ero ayelujara lose to koja ni egbe oselu ...
Read More »Fìdáù Ajímọ̀bi, ẹbí nìkan ní wọ́n ń retí–Ẹbí Ajímọ̀bi
Fìdáù Ajímọ̀bi, ẹbí nìkan ní wọ́n ń retí–Ẹbí Ajímọ̀bi Ṣé wọ́n ní kìí jẹ́ ti baba t’ọmọ, kó mọ́ ní ààlà. Èyí ló díá fún bí àwọn ẹbí olóògbé Abíọ́lá Ajímọ̀bi tí sàlàyé pé ,kí àwọn olùkẹ́dùn, ó má wulẹ̀ ...
Read More »È̩yin òsìsé̩ mi nílò àyè̩wò coronavirus kíákíá- Akeredolu
È̩yin òsìsé̩ mi nílò àyè̩wò coronavirus kíákíá – Akeredolu Arakunrin Rotimi Akeredolu ti o je gomina ipinle Ondo lo n gba awon alabasise re niyanju ki won fi oro ti oun se arikogbon. O ni iba lasan ni o se ...
Read More »Àwo̩n aké̩kò̩ó̩ ti lè wo̩lé, mótò ti lè rìn làti ìpínlè̩ sí ìpínlè̩ – NCDC
Àwo̩n aké̩kò̩ó̩ ti lè wo̩lé, mótò ti lè rìn làti ìpínlè̩ sí ìpínlè̩ – NCDC Ijoba apapo ti fowo si aba ti awon ajo NCDC gbe lo si odo Aare. Ijoba fi aaye sile ki awon ara ilu maa rin ...
Read More »Keyamu àti àwo̩n Asojú sòfin tutó̩ sí ara wo̩n lójú
Keyamu àti àwo̩n Asojú sòfin tutó̩ sí ara wo̩n lójú Minisita fun ipinle ati eto ise ni orileede yii, Agbejoro agba Festus Keyamu ni awon Asoju sofin ranse si ni ilu Abuja lonii. Won fi saarin, won si bere si ...
Read More »Mí ò ì pinnu lóri ìdíje Ààrẹ ọdún 2023-Tinubu
Mí ò ì pinnu lóri ìdíje Ààrẹ ọdún 2023-Tinubu Báá ti ṣe làá wí, ẹnìkan kìí yan àna rẹ̀ lódì ni Yorùbá wí àsamọ̀ yìí ló díá fún bí asáájú ẹgbẹ́ òṣelú ẹgbẹ́ APC, Sẹ́nétọ̀ Bola Ahmed Tinubu tí ṣọ ...
Read More »Ògún Majek wọ káà ilẹ̀ sùn
Ògún Majek wọ káà ilẹ̀ sùn Ọlọ́jọ́ ń kajọ́, ẹ̀dá ò fiyè si.Ìjọ ọmọ tuntun dáyé, nijọ́ ìdùnnú, ẹ̀rín, òhun ọ̀yàyà fún ẹbí,ará, pẹ̀lú ìyekan. Ṣùgbọ́n kìí rọgbọ ká sàdédé sàfẹ̀kù èèyàn ẹni pékú yọwọ́ ọ rẹ̀ ní dúníyàn. Àsamọ̀ ...
Read More »Abiola Ajimobi sùn un re
Ikú pàgbẹ̀ àṣírí aláró tú.Ikú pàlùkò àbùkù kará ìkosùn.Ọrùn má kánjú, gbogbo wa la dágbádá ikú.Ìgbà átàsìkò ẹ̀dá ló só kùnkùn.Gíńgín ladáhunṣe tó mewé e re.Gbogbo wa lòpè nípa àkúnlẹ̀yàn.Òkú ń sunkú òkú, akáṣọlérí ń sunkú ara a wọn.Sùn un ...
Read More »