Ogogorun awon olugbe ti ẹya Indian ilu ibi ti Ọdọkùnrin ti kú, eyi ti won fura si wipe olo aloju oògùn, eyi ti o si fa rogbodiyan larin awon ati awon omo orilende ti ile Afirika eyin won un se ...
Read More »
Àṣà Oòduà, Asa Ibile Oòduà. Oòduà (Yoruba) je okan ninu awon eya ti o laju ju lode aye yi. Lati igba ti alaye ti daye ni won ti ni eto ati ilana to kun nipa ohun gbogbo ti won nse ni igbesi ayee won.
ayangalu Comments Off on Agbajopo Ibinu da ija Eneya-meya si le, Eyi ti o mu emi Omokurin ka lo ni ilu ‘India’.
Ogogorun awon olugbe ti ẹya Indian ilu ibi ti Ọdọkùnrin ti kú, eyi ti won fura si wipe olo aloju oògùn, eyi ti o si fa rogbodiyan larin awon ati awon omo orilende ti ile Afirika eyin won un se ...
Read More »ayangalu Comments Off on What Ifa says in Eji Ogbe
“You call yourself a Babalawo! You send friend request to people You chat them up You asked them if they wish to consult Ifa You said you wish to help them ask about their guardian Orisa What???? Ifa said in ...
Read More »ayangalu Comments Off on “Ìpolongo tó nlọ lọ́wọ́ ni orilẹ́ èdè Nigeria ni pe“Àyípadà bẹ̀rẹ̀ pẹ̀lú mi”
Ohun ti wọ́n bá fi ogún ọdún tàbi ju bẹ́ ẹ̀ lọ kọ́, ṣe é bàjẹ́ ni iṣéjú akàn, ṣùgbọ́n lati ṣe àtúnṣe lè gba ọ̀pọ̀lọpọ̀ ọdún bakan na a. Ó ṣe pataki ki gbogbo ọmọ ilú pinu ni ikan ...
Read More »ayangalu Comments Off on Obinrin kò ṣe e jánípò si ìdí Àdìrò nikan, Obinrin ló ni gbogbo Ilé
Ìtàn fi yé wa wi pé Yorùbá ka ọ̀rọ̀ obinrin si ni àṣà Yorùbá bi ó ti ẹ jẹ wi pé obinrin ki jẹ Ọba nitori ni àṣà ilú, ọkunrin ló njẹ olóri. Obinrin kò pọ̀ ni ipò agbára. Àwọn ...
Read More »ayangalu Comments Off on Omo Egbe Yoruba ati ‘OPC’ (Oodu Peoples Congress) Fajuro lori rogbodiyan ti o sele ninu ile ife
Awon omo egbe apapo-Yorùbá-titi eka –oselu, Afenifere ati awọn omo egeb (Oodua Peoples Congress), OPC, ti fariga nipa rogbodiyan ti oun lo ni ilu Ile Ife. Ninu oro kan ti abenugo fun eggbe Afenifere kán so eyi ti un se ...
Read More »ayangalu Comments Off on Ti eba jabo si inu omi pelo ọkọ ayọkẹlẹ: Eleyi ni ona irọrun ti elefi gba emi yin la (Fidio)
Eleyi ni ona irọrun ti elefi gba emi yin la, ati ligba ti eba jabo si nu omi eyin ati ọkọ ayọkẹlẹ yin. A se iwadi wipe egbelegbe irinwo “400” awon eniyan ni ounku ni ododun lipa ijamba awon ati ...
Read More »ayangalu Comments Off on Posita gbigba okore pada Kun ilu Port-Harcourt Egba ni eleja
Posita wagba okore kun igboro ilu Port-Harcourt
Read More »ayangalu Comments Off on Eyin eniyan e wo E-moni(E-money) ninu photo titun re.
Alaga ti Ẹgbẹ eka marun apapo , wuni ninu poto re titun ti o sese ya.
Read More »ayangalu Comments Off on Tonto Dikeh ki Mercy Johnson pe ‘oku orire fun ipo titun ti Gomina Kogi sese yan si’.
Awuyewuye ija ti oun lo laarin awọn oṣere Tonto Dikeh ati Mercy Johnson, Tonto Dikeh ti toro aforiji lori awọn gbólóhùn o ṣe nipa ọmọ rẹ ati awon oro miran to ti so ni odun die seyin. Mercy Johnson gba ebe ...
Read More »Awon ‘SON’ (Standards Organisation of Nigeria) ti mu ogbeni akeruwole ti oun ta aye deru Kosimetik ati ọti-waini ti se ayipada awọn ogun ti ọjọ ti lo lori wọn ati ti o nri titun ọjọ lori wọn, ni eyi ti ...
Read More »
Ọmọ Oòduà Naija Gist | News From Nigeria | Entertainment gist Nigeria|Networking|News.. Visit for Nigeria breaking news , Nigerian Movies , Naija music , Jobs In Nigeria , Naija News , Nollywood, Gist and more