A ku imura! Awo Alaseye! Isese o, o ti d’ogererere! Awo aseye l’eyin Baba wa o maa se! Aase! K – Awodiran Agboola IyaOgbe OmoEdu Yeyelufe Oyewole
Read More »
Àṣà Oòduà, Asa Ibile Oòduà. Oòduà (Yoruba) je okan ninu awon eya ti o laju ju lode aye yi. Lati igba ti alaye ti daye ni won ti ni eto ati ilana to kun nipa ohun gbogbo ti won nse ni igbesi ayee won.
ayangalu Comments Off on Awo aseye l’eyin Baba wa o maa se!
A ku imura! Awo Alaseye! Isese o, o ti d’ogererere! Awo aseye l’eyin Baba wa o maa se! Aase! K – Awodiran Agboola IyaOgbe OmoEdu Yeyelufe Oyewole
Read More »ayangalu Comments Off on Orisa Alaase, Igbakeji Olodumare
| | | | | | | | | | | | | Ekaaro eyin eniyan mi, aojiire bi? Aku ise ana o, a sin tu ku isimi alayo loni eledumare yio funwa ni isimi to peye ...
Read More »ayangalu Comments Off on Oruko kan fu foto yi ?
Oruko kan fu awon arakurin yii ?
Read More »ayangalu Comments Off on Aja To Rele Ekun To Bo..
Aja ti o ba rele ekun ti o si pada lai f’arapa ti iru aja be o si le gbegba ope olowo aja be ni yoo fi se ounje ajesun laipe ojo. KABIYESI ILU MOYE ni a o ba maa ...
Read More »ayangalu Comments Off on Oriki Ibeji
Wíníwíní lójú orogún Ejìwọ̀rọ̀ lojú ìyá ẹ̀, Ẹ̀jìrẹ́ ará ìṣokún, Ẹdúnjobí, ọmọ a gbórí igi rétẹréte, Ọkàn ń bá bí méjì ló wọlé tọ míwá, Ọ́bẹ́kíṣì bẹ́kéṣé, Ó bé sílé alákìísa, Ó salákìísà donígba aṣọ. Gbajúmọ̀ ọmọ tíí gbàkúnlẹ̀ ìyá, ...
Read More »ayangalu Comments Off on Odu Ifa Owonrinwofun/ Ofun
| | | | | | | | | | | | Ekaaro eyin eniyan mi, aojiire bi? Aku ise ana o a sin ku isimi opin ose emin wa yio se pupo re laye o ase. Odu ifa ...
Read More »ayangalu Comments Off on #CelebratingOsun
Ladekoju Oore Yeye Osun o! E ku odun o! Osun Sengese Oyeyenimo a gbe wa o! Aase! Photo Cc – Bekky Amusa
Read More »ayangalu Comments Off on Odu Ifa Owonrin Tutu/ Oturupon
| | | | | | | | | | | | | Ekaaro eyin eniyan mi, aojiire bi? Aku ise ana o, eledumare yio gbo adura wa o yio si bawa tu ile aye to ...
Read More »ayangalu Comments Off on “Wun ó l’ówó l’ówó n tó máalo….
“Wun ó l’ówó l’ówó n tó máalo Wun ó bí’mo lé’mo n tó máalo Wun ó n’íre gbogbo n tó máalo Bí Wón n n’íre lórun èmi ò mò Wun ó n’íre gbogbo n tó máalo I will have enough ...
Read More »
Ọmọ Oòduà Naija Gist | News From Nigeria | Entertainment gist Nigeria|Networking|News.. Visit for Nigeria breaking news , Nigerian Movies , Naija music , Jobs In Nigeria , Naija News , Nollywood, Gist and more