Itan Omooba Amoke
Omooba obinrin kan gbe ni ilu alayo, orewa pupo ju oruko re si nje Amoke ni ile Yoruba atijo. Orewa pupo debi pe gbogbo okunrin ilualayo niwon ko enu ife si, koda awon okunrin ilu agbegbe won gan o gbeyin. ...
Read More »Àwàdà kẹrí-Kẹrì ni àwọn kọmití tó ní mi ò lè díje du ipò gómìnà APC ni 2026 n ṣe – Omisore
Yínká Àlàbí Awọn kọmiti to n ṣe àyẹ̀wò awọn oludije du ipo gomina labẹ ẹgbẹ́ oselu APC ti ja igbakeji gomina tẹlẹ ni ipinle Osun, Alagba Iyiola Omisore ati awọn mẹfa miiran.Wọn ni iwe wọn ko pe lati dije du ...
Read More »Kọ́mi n’Yoòbá || Season 1 || Episode 4
Kọ́mi n’Yoòbá || Season 1 episode 3..
Ọ̀gbẹ́ni Olaoye déèdé pòórá nílé ìtura kan nílùú Akure
Fẹ́mi Akínṣọlá Ádùrá tí a máa ń ṣe ni pé kí á má rin àrin f’ẹsẹ̀sí.Mọ̀lẹ́bí ọkùnrin kan, Ògbẹ́ni Olaoye Olatunde, tó jẹ́ igbákejì ọ̀gá àgbà ilé ẹ̀kọ́ girama kan nílùú Ọwọ ti ké gbàjarè pé ọkùnrin náà di àwárítì ...
Read More »Kọ́mi n’Yoóbá
Àwòrán Láti Ibi Ètò Ẹlẹ́kùnjẹkùn
Díẹ̀ lára àwọn àwòrán láti ibi ètò Ẹlẹ́kùnjẹkùn tó wáyé ní ìlú Èkó lánàá. *Ìṣọ̀kan lọkọ̀ ìlọsíwájú
Read More »Iṣẹṣe Kọ́jọ́dá/calendar – Fún Oṣù Ẹ̀bìbí/May 2025.
TÍ OSU TITUN BÁ DÉ, ARÁYÉ MÁA Ń YỌ̀ MỌ́ NI, WỌN MÁA BÁ GBOGBO WA YỌ AYỌ̀ IRE NÍNÚ OSU TITUN YÍÌ, PẸ̀LÚ ÀṢẸ ELÉDÙMARÈ . 1. Ọbàtálá/Òrìṣà-ńlá, Ọbalúayé/Ṣàpọ̀nná, Ògìrìyàn, Egúngún, Ìyàmi Àjẹ́. 2. Ifá, Ọ̀rúnmìlà, Èṣù-Ọ̀dàrà, Orí, Odù, ...
Read More »Jíjẹ́ olókìkí ní ọmọdé jẹ́ ẹrù wúwo púpọ̀ – Lil Kesh
Mary Fágbohùn Gbajugbaja olorin Naijiria, Keshinro Ololade, ti gbogbo eniyan mọ si Lil Kesh, ti sọrọ nipa didi olokiki bi ọdọmọkunrin. Olorin ‘Young And Getting It’ ṣàlàyé pé ṣíṣe àṣeyọrí ní kékeré jẹ́ “eru wuwo.” Lil Kesh ṣe ifihan eyi ...
Read More »
Ọmọ Oòduà Naija Gist | News From Nigeria | Entertainment gist Nigeria|Networking|News.. Visit for Nigeria breaking news , Nigerian Movies , Naija music , Jobs In Nigeria , Naija News , Nollywood, Gist and more










