Mo ki gbogbo wa pata lokunrin ati lobinrin, lomode ati lagba wipe a ku ise oni, a si ku abo sori eto wa eto yin, eto Odo Iwoyi ti ose yi. E wa nkan fidile tabi ki e gbiyanju fidile ...
Read More »
Àṣà Oòduà, Asa Ibile Oòduà. Oòduà (Yoruba) je okan ninu awon eya ti o laju ju lode aye yi. Lati igba ti alaye ti daye ni won ti ni eto ati ilana to kun nipa ohun gbogbo ti won nse ni igbesi ayee won.
ayangalu Comments Off on Odo Iwoyi – E Gbo Bi Atejise Na Ti Lo
Mo ki gbogbo wa pata lokunrin ati lobinrin, lomode ati lagba wipe a ku ise oni, a si ku abo sori eto wa eto yin, eto Odo Iwoyi ti ose yi. E wa nkan fidile tabi ki e gbiyanju fidile ...
Read More »ayangalu Comments Off on Arun Karun Konifile Awa Se Ibugbe o
Eyin tiaa..akuu gbalegbata oni o…arun karun konifile awa se ibugbe o. Ase..Paronure lawaa..Se e gbagbe pe lati onilo di ola.faaji nson. Leyin Elere ti okan yin yan laayo. Pe kowa kolu siwa nibadi. Emaa gbagbe pe.idalu niselu. Onje tin lo ...
Read More »Mo ki gbogbo wa pata lokunrin ati lobinrin, lomode ati lagba wipe a ku ise oni, a si ku abo sori eto wa eto yin, eto Idile Alayo ti ose yi. E wa nkan fidile tabi ki e gbiyanju fidile ...
Read More »ayangalu Comments Off on Eeto Owe L’esin Oro
YAKUB BUKKY – Nje a tun ti de loni gegebi ise wa ni gbogbo ojoru. Oro enikokan wa koni dojuru oo (amin), a ki gbogbo kaabo si akootun eeto yin, eeto wa owe l’esin oro, oro l’esin owe, ti oro ...
Read More »ayangalu Comments Off on Iwure Owuro Toni 04-05-2016
E MAA WI TELE MI : ……… *Owo ko ni ri mi sa. *Oju owo ko ni pon mi. *Ojo ibukun mi ko ni di ojo abuku. *Alaaanu mi ko ni ko’yin si mi. *Edumare ma je ki n teni ...
Read More »ayangalu Comments Off on Iwure Osu Tuntun 01-05-2016
E MAA WI TELE MI : ……… *Osu karun-un yii, osu ire owo ni fun mi. *Osu ire ile kiko ni fun mi. *Osu ti maa ra oko ayokele. *Osu igbega lenu ise mi ni. *Osu idunnu ni yoo je ...
Read More »ayangalu Comments Off on Ibeere Toni
Egbo eyin o ogbon,…nje oda ki Iyawo ile o mo ko orun fun okore ? ….tabi ki oko naa o ko fun Iyawo re?……. Iru nkan wonyi se o ma ndin Ife Ku ni abi oma tubo mufe gbile si???????????
Read More »ayangalu Comments Off on Oko mi ati iya re loba aye mi je
Akole oke yi lo se apejuwe oro arabinrin kan , eyi to fi esun kan iya oko re wipe o gba arisiki oun fun omo (oko re) Nigbati obinrin yi so oro , emi bi leere wipe SE OKO SAA ...
Read More »ayangalu Comments Off on Iwure Owuro Ipari Osu
E MAA WI TELE MI : ….. *Airije-airimu nile aye mi ti dopin. *Ibanuje ninu aye mi ti dopin. *Ijakule ninu aye mi ti dopin. *Ise mi ko ni dojuru *Ogun aye ko ni borii mi. *Oju owo ko ni ...
Read More »ayangalu Comments Off on Kabiesi sango o,arabambi arigba ota segun !
Sangiri Lagiri Olagiri kaka figba edun bo Inan Loju Inan lenu Oloju orogbo eleeke obi A tu won ka nibi tiwon gben danan iro….Sango onikoso ooo Happy ose sango day to all onisese here in Nigeria and diaspora?❤️?❤️?????
Read More »
Ọmọ Oòduà Naija Gist | News From Nigeria | Entertainment gist Nigeria|Networking|News.. Visit for Nigeria breaking news , Nigerian Movies , Naija music , Jobs In Nigeria , Naija News , Nollywood, Gist and more