E tun gbe yewo, Gomina Foyose tun gbe sunmo iya eleja.
Read More »
Àṣà Oòduà, Asa Ibile Oòduà. Oòduà (Yoruba) je okan ninu awon eya ti o laju ju lode aye yi. Lati igba ti alaye ti daye ni won ti ni eto ati ilana to kun nipa ohun gbogbo ti won nse ni igbesi ayee won.
admin Comments Off on Fayose niso eleja
E tun gbe yewo, Gomina Foyose tun gbe sunmo iya eleja.
Read More »admin Comments Off on Oba’binrin Asa Solaade Iyaasa: Ohun IFA ati Iwure
ÒÒṢÀ ÒKÈ, ÌBÀ IFA ni ti a ba ji a ki OLU OLU moji mo ki o loni IFA ni to a ba ji a ki Osin, osin moji mo ki o loni ELA ni kan ni somo bibi inu ...
Read More »admin Comments Off on Omo Gomina Ambode n je igbaladun Sande lowo
Kosi ise lonii ojo Sande l’Alausa. Ile ni Habib Aruna, akowe iroyin fun gomina Akinwunmi Ambode, wa pelu aya re. Awon mejeeji jo n je igbaladun ara won loni miliki.Ki lo tile kan mi na lori oro oko ati iyawo ...
Read More »admin Comments Off on Awon Foto Kunle Afolayan niluu Kenya
Die ni yii ninu ibudo ere fiimu tuntun Kunle Afolayan, The CEO, ni ilu Nairobi to wa ni Kenya.
Read More »admin Comments Off on E wo ohun ti won so nipa Basiru Alaaru niluu Abuja
admin Comments Off on Oju oge orekelewa iyawo K1 oba Fuji tasansan
Titi Masha ni yii, okan ninu awon orekelewa obirin ti K1 de Ultimate fi n segbaladun niyewu. Titi rewa pupo lobirin, oju re ri rekete bi ojo, ibadi aran ti n danilorun nigba gbogbo. [Olayemi, ara n fu mi si ...
Read More »admin Comments Off on E wo ohun ti Gomina Ambode ko fun awon agbofinro ilu Eko
Gomina Ambode ti ilu eko ti ko opolopo ohun elo bi moto, oko ojuomi, oko ofurufu ati okada fun awon agbofinro ipinle naa lati le gbogun ti iwa idaran ni ipinle naa. Minisita fun eto abenu, Rahman Dambazzau lo soju ...
Read More »admin Comments Off on Ojulowo-ogidi iya je awon ole ti won mu ni Mowe
Ojo gbobo ni tole, ojo kan pere ni tolohun. Owo palanba awon igara olosa kan segi laaro ana ni agbegbe Olowotedo Mowe to wa ni masose Eko si Ibadan. Ikanra ni awon eniyan agbegbe naa fi na awon ole taa ...
Read More »admin Comments Off on Egan dogo: Omobirin ti o lese n pa $1000 lojumo
admin Comments Off on Awon aye tun pade Fayose nile alapata
Gomina ipinle Ekiti, Ayodele Peter Fayose tun gbe ara mii yo pelu bo se gba obe alapata mu niso alapata eran to si bere si ni ge eran fun awon kositoma.
Read More »
Ọmọ Oòduà Naija Gist | News From Nigeria | Entertainment gist Nigeria|Networking|News.. Visit for Nigeria breaking news , Nigerian Movies , Naija music , Jobs In Nigeria , Naija News , Nollywood, Gist and more