Àfòròdárà (Rapper) Gucci Mane àti Keyshia Ka’oir se ìgbéyàwó alárinrin tí ó jé wípé ogún-l’ógbòn àwon ènìyàn ni won wò ó n’ílé l’óko lórí èro amóhùnmáwòrán.igbéyàwó náà rinlè gan tí ó fi jé wípé àwon ènìyàn jàkànjàkàn ...
Read More »
Àṣà Oòduà, Asa Ibile Oòduà. Oòduà (Yoruba) je okan ninu awon eya ti o laju ju lode aye yi. Lati igba ti alaye ti daye ni won ti ni eto ati ilana to kun nipa ohun gbogbo ti won nse ni igbesi ayee won.
Awoyemi Bamimore Comments Off on Àwòrán ìgbéyàwó ògbóntarigì olórin afòròdárà tí orúko rè n jé Gucci mane .
Àfòròdárà (Rapper) Gucci Mane àti Keyshia Ka’oir se ìgbéyàwó alárinrin tí ó jé wípé ogún-l’ógbòn àwon ènìyàn ni won wò ó n’ílé l’óko lórí èro amóhùnmáwòrán.igbéyàwó náà rinlè gan tí ó fi jé wípé àwon ènìyàn jàkànjàkàn ...
Read More »Ònlò èro ayélujárá ( Facebook) tí a mò sí Arc Pashal Chike Umeobi ló so wípé arábìnrin yí ni owó àwon figilanté tè ní Ezinifite , ìlú kan ní ìpínlè Anambra . Arábìnrin yí ni won fi ...
Read More »Awoyemi Bamimore Comments Off on Omokùnrin Wizkid , Ayo kékeré òun àti ìyá rè múra jáde nínú aso orílé èdè Nàíjíríà .
Binta Diallo àti omokùrin rè ,king Ayo kékeré jáde lo láìpé tí won sì tàn gan nínú Dashiki won àti aso orílè èdè Nàíjíríà. Aso orílè èdè Nàíjíríà yí jé kí ó dà bi omo Yorùbá tí ó ...
Read More »Awoyemi Bamimore Comments Off on Nígbà tí adékódère bá padà s’ábúlé .
Òpò omoge òde-ìwòyé ni a bí sí abúlé sùgbón bí won bá ti jáde díè ìwà àti ìsesí won yóò y’àtò, won á sì gbàgbé orísun won. ...
Read More »Ní òní mo gbèrò láti tún ilé àti àyíká Adìe mi se, ni mo pàdé afayàfà yí, mo sá eré bí mo se le sa mo. Nítorí ìgbà àkókò mi rè é tí mà rí ejò ńlá báyìí láàyè, tí ...
Read More »Timi Àgbàlé, olóde tí ó sì jé jagunjagun tí Aláàfin rán lo sí ìlú Ede láti dáàbò bo àwon ènìyàn ibè. Alágbára ènìyàn ni Timi jé , tí a sì mò ó sí *Timi Àgbàlé olófà-iná*,gégé bí ìtàn se so, ...
Read More »Awoyemi Bamimore Comments Off on Odó kàyééfi ńlá tí ó wà ní *ADO AWAYE*.
Ìlú kéréje kan wà ní ìpínlè Oyo tí orúko ìlú náà sì ń jé *ADO AWAYE*, òdó kàyééfi kan wà ní ìlú yí tí ó jé wípé bí ènìyàn bá ti esè kan bo inú rè yóò fa eni náà ...
Read More »Awoyemi Bamimore Comments Off on Òdómokùnrin odún mókàndílógún (19 years) fé odómobìnrin odún méèdógún (15 years) ní ilè àríwá (North) ní orílè èdè Nàìjíríà.
Àwòrán tí ó gba aféfé ni ti àwon tokotayà yí tí oko jé odún mókàndílógún tí ìyàwó sì jé odún méèdógún ní ilè àríwá orílè èdè Nàìjíríà. Ò n lò èro ayélujàra kan ni ó pín àwòrán tokotayà yí, tí ...
Read More »Awoyemi Bamimore Comments Off on Àwon apàse ilé-ìwé Obafemi Awolowo University (OAU) pàse kí won mú àwon akékòó látàrí àtakò àláfíà (peaceful protest) tí won ń se.
Ogbà Obafemi Awolowo University (OAU) ti kó sí inú dàrúdàpò nígbà tí òpò akékòó tò lo sí àgó olóòpá tí ó wà ní Moore ní ìlú ile-ife láti bèèrè fún ìdásílè àwon akegbé won tí àwon ìgbìmò ìdábòbò Ogbà náà ...
Read More »Awoyemi Bamimore Comments Off on Àwòrán ìsìnkú Odudu Davis, olóòpá tí ìbon àwon olóòpá ojú omi bà tí ó sì kú ní ìpínlè calabar.
Ní’sàlé ni àwòrán ìsìnkú olóyè nínú ológun (Corporal) Odudu Davis tí ìbon pa nígbà tí osù kàrún di ogbòn ní inú odún yìí (30/5/2017)láti owó àwon olóòpá ojú omi (naval officer) nígbà tí àwon olóòpá àti àwon olóòpá ojú ...
Read More »
Ọmọ Oòduà Naija Gist | News From Nigeria | Entertainment gist Nigeria|Networking|News.. Visit for Nigeria breaking news , Nigerian Movies , Naija music , Jobs In Nigeria , Naija News , Nollywood, Gist and more