Home / Art / Àṣà Oòduà / Ejò tí mo pa nínú ilé Adìe mi lóòní.

Ejò tí mo pa nínú ilé Adìe mi lóòní.

Ní òní mo gbèrò láti tún ilé àti àyíká Adìe mi se, ni mo pàdé afayàfà yí, mo sá eré bí mo se le sa mo. Nítorí ìgbà àkókò mi rè é tí mà rí ejò ńlá báyìí láàyè, tí kìí bá se lopélopé omokùnrin kan tí mo pàdé, mo rò wípé ejò náà kò bá bó mó mi lówó.
Èyin tí e n’ìfé Ejò n’ílé irú èyà wo ni eléyìí báyìí..

About Awoyemi Bamimore

2 comments

Viral Video

Support Ooduarere

SUPPORT OODUARERE
Scan QR code below to Donate Bitcoin to Ooduarere
Bitcoin address:
1FN2hvx5tGG7PisyzzDoypdX37TeWa9uwb
x

Check Also

ajegunle

List Of Ajegunles In Oodualand (Yorubaland)

LAGOS STATE:Ajegunle, Ajeromi/Ifelodun LGAjegunle, Alimosho LG OSUN STATE:Ajegunle, Ife South LGAjegunle, Obokun LGAjegunle, Ola Oluwa LGAjegunle, Olorunda LGAjegunle, Orolu LGAjegunle, Ayedaade LGAjegunle, Boluwaduro LG KOGI STATE:Ajegunle, Ekinrin Ade, Ijumu LG OGUN STATE:Ajegunle, Ifo LGAjegunle, Ipokia LGAjegunle, Yewa.S LGAjegunle, Ado Odo/Otta LGAjegunle, Ewekoro LGAjegunle, Ikenne LGAjegunle, Odeda LGAjegunle, Sagamu LG ONDO STATE:Ajegunle, Ondo.W LGAjegunle, Idanre LGAjegunle, Ilaje LGAjegunle, Ile Oluji LGAjegunle, Odigbo LGAjegunle, Ose LGAjegunle, Akure South LGAjegunle,Okitipupa OYO STATE:Ajegunle, Ibarapa North LGAjegunle, Afijio LGAjegunle, Atiba LGAjegunle, Oriire LGAjegunle, Surulere LGAjegunle, ...