Èyí ni ìròyìn ipò tí ilé-ìwòsàn ńlá wà ní warri ní ìjoba ìpínlè Delta wà lówólówó . Àwòrán na jé pínpín sí orí èro ayélujàra (facebook) English Version Continue after the page break
Read More »
Àṣà Oòduà, Asa Ibile Oòduà. Oòduà (Yoruba) je okan ninu awon eya ti o laju ju lode aye yi. Lati igba ti alaye ti daye ni won ti ni eto ati ilana to kun nipa ohun gbogbo ti won nse ni igbesi ayee won.
ayangalu Comments Off on Ipò Burúkú Ti Ilé-ìwòsàn Ńlá Ní Warri Ní Ìjoba Ìpínlè Delta Wà.
Èyí ni ìròyìn ipò tí ilé-ìwòsàn ńlá wà ní warri ní ìjoba ìpínlè Delta wà lówólówó . Àwòrán na jé pínpín sí orí èro ayélujàra (facebook) English Version Continue after the page break
Read More »ayangalu Comments Off on Ilé Tí Won Ń Kó Lówó Wó Ní Ilorin.
Èrù ti ń ba àwon òpòlopò ènìyàn bóyá àwon ènìyàn kú sí inú ilé tí won ń kó lówó ní òpópónà Stella, Tanke ,Ilorin ,ní ìjoba ìpínlè Kwara tí ó wó ní òsán yí. English version Continue after the page ...
Read More »ayangalu Comments Off on Àwon fúlàní darandaran kolu àwon àgbè oníresì (Rice farmer) ní ìjoba ìpínlè Benue.
–Tí ó sì dá àpá sí won l’ára. Nígbà tí a wà lénu síse àtakò àláfíà sí ilé ìjoba Makurdi lóòní láti jé kí ìjoba gbárùkù láti jé kí won f’owó sí owó ntanràn jíjeko (Anti grazing bill) sínú ...
Read More »ayangalu Comments Off on Kcee tú àsírí pé òhun ni olórin àkókò ní ìròlé èdè Nàìjíríà tí ó kókó lo okò bògìnì tí a mò sí Rolls-Royce phantom nínú fídío Orin rè.
Gbajúgbajà olórin, Kcee o ní ìràwò márùn-ùn. Nínú Orin tí ó ti se jé kí á rí àsírí rè gégé bí àsáájú tí ó kókó lo okò bògìnì “Rolls-Royce ní ilé-isé olórin ní orílè èdè Nàìjíríà. Òun ni ó ...
Read More »ayangalu Comments Off on Àwòrán Obanikoro àti Oluremi Tinubu àti àwon omo egbé APC tó kùn ní ìlú èkó.
Ní ìsàlè yìí ni àwòrán sineto Obanikoro àti sineto Oluremi Tinubu àti àwon tó kùn. Ní ìpàdé kejilélógún (22nd) ní ibi ìpàdé àwon sinetò ní agbègbè èkó …. English Version after the page break
Read More »ayangalu Comments Off on Inú àwon olólùfé 2baba dùn púpò nígbà tí won rí olólùfé won ní Glomega music tour tí ó wáyé ní Victoria Island, ní ìlú èkó.
Gbajúgbajà olórin 2baba jé òkan lára àwon tí ó korin ní Glomega tour ní VI ní ìlú èkó. Ó tún wú àwon ònwòran lórí nígbà tí ó f’akoyo lórí ìtàgé. Ewo àwòrán bí ó se Ń dá won lárayá n’ísàlè.. ...
Read More »ayangalu Comments Off on Àwon olólùfé Biodun Okeowo wí fun pé kí ó pa àwòrán rè tí ó wo aso tí ó fun ré.
Òsèré Biodun Okeowo tí a mò sí Omobutty, ni àwon olólùfé rè ń sòrò sí látàrí àwòrán tí ó pín ní bi tí ó ti wo aso tí ó gbé èyà ara rè jáde… Continue after the page break for ...
Read More »ayangalu Comments Off on Akékòó Odún Keta (300l) Ti Oau Ti Eka Èkó ‘Pharmacy’ Rì Sómi, Tí Ó Sì Kú Sí Odò-ìwè (Swimming Pool) Ní Hòtéèlì.
Akékòó odún keta (300l) ti eka èkó pharmacy, Obafemi Awolowo University; pàdánù èmí rè Lánàá léyìn ìgbà tí ó rì sómi nínú odò-ìwè (swimming pool) ní hòtéèlì tí a mò sí Hilton. A mò ó sí Fatile Emmanuel. Ìsèlè yí ...
Read More »ayangalu Comments Off on Ìkan Lára Àwon Ìyá Ń Dá Gbé (Single Mum) Orílè Èdè Nàìjíríà Múra Bíi Okùnrin Láti Se Ayeye Àjòdún Baba (Father’s Day).
Ò n lo èro ayélujàra (facebook user) Ebere Amalaha tí ó ń jé ìyá ń dá gbé, múra bíi okùnrin láti se ayeye àjòdún baba tí ó wáyé ní ojó kejìdínlógún osù kefà (June 18). Pín àwòrán ara rè bí ...
Read More »ayangalu Comments Off on Òrékùnrin Àtijó Vera Sidika Fi Ìhòhò Rè Hàn Látàrí Pé Ó Fi Sílè Bá Olówó Kan Ní Nàìjíríà Lo.
Léyìn wíwá ènìyàn pàtàkì ní ìlú Kenya ,Vera Sidika pín àwòrán tí ó fi hàn wípé kò bá ti tún gbàgbé odómokùnrin míràn ní orílè èdè Nàìjíríà tí owó kún àpò rè. òrékùnrin àtijó rè dapadà fún un nípa pínpín ...
Read More »
Ọmọ Oòduà Naija Gist | News From Nigeria | Entertainment gist Nigeria|Networking|News.. Visit for Nigeria breaking news , Nigerian Movies , Naija music , Jobs In Nigeria , Naija News , Nollywood, Gist and more