Home / Art / Àṣà Oòduà (page 83)

Àṣà Oòduà

Àṣà Oòduà, Asa Ibile Oòduà. Oòduà (Yoruba) je okan ninu awon eya ti o laju ju lode aye yi. Lati igba ti alaye ti daye ni won ti ni eto ati ilana to kun nipa ohun gbogbo ti won nse ni igbesi ayee won.

ifa

Edi Alálà !!!

Ekaaro eyin eniyan mi, aojiire bi? aku ijosin ifa toni to je ojo abameta, Olodumare ninu aanu re koni da emin wa legbodo lati le se pupo ijosin naa loke erupe o Ase. Idanileko ti aaro yi jade lati inu ...

Read More »
ooni-ile-ife

Ọọ̀ni Kò Ṣe Rífín ! (Apá Kìíní Lati Ọwọ́ Daniel Adefare)

Oríadé, ọrùn-ìlẹ̀kẹ̀, gbogbo ẹ̀yin ajunilọ mo júbà o. Àwọn àgbà bọ̀ wọ́n ní “Kíkéré labẹ́rẹ́ kéré, kìí ṣe mímì fádìyẹ” Káláyé tó dáyé, kékeré kọ́ ni Bàbá fi ju ọmọ lọ. Ọọ̀ni kìí ṣe ẹgbẹ́ ọba kọ́ba gẹ́gẹ́ ìtàn ti ...

Read More »
aje

Iwure ojo ajé toni jade ninu odu mimo ogbe onigun.

Ekaaro eyin eniyan mi, aojiire bi? Aku isimi ana o, Olodumare yio funwa nisinmi o, bi oni se je ojo ajé ao raje sokun ao raje sede ao si raje saiku baale orò o Ase. Iwure ojo ajé toni jade ...

Read More »
asa yoruba

Oríkì Àjọbí, Àṣà Yorùbá ti ó Nparẹ́ lọ

Oríkì* jẹ ọ̀rọ̀ ìwúrí ti Yorùbá ma nlò lati fi sọ ìtàn àṣà àti ìṣe ìdílé lati ìran dé ìran. Ninú oríkì ni a ti lè mọ ìtàn ìṣẹ̀dálẹ̀ ẹbí ẹni àti ohun ti a mọ ìdílé mọ́, bí i ...

Read More »
olopa-pa-obirin-ni-ilu-eko

Olopa pa obirin kan ni ilu Eko

Olopa yinbon pa iyawo ile kan , ni adugbo kan ti aun pe ni Onipanu ni ilu Eko, nigba ti oun le ikan ninu awon omo ti won ma un fi ero ayelujara jale. Awon agbofinro so wipe won yi ...

Read More »
us agression in syria middle east 1

Orile ede, Russia, Iraq ati Syria, Fa oju ro si orile-ede Amerika.

Ijoba ile America ti se igbekale dosinni ti (Tomahawk) oko ohun ija ofurufu ni Siria, eyi ti awon kan ti oruko won un je (Pentagon) mo nipa re ni Ọjọbọ Ni ibamu si osise, (Washington) so wipe kemikali ija ikolu ...

Read More »

Agun Baniro So wipe, Ilu Eko ni Olulu Ipinle Abuja Wa

Aara meriri, egbani eleja, arabirin kan ti o un se agun ba ni ro so wipe olulu ipinle Enugu Ni Anambra, ati pe o tun so wipe, olulu ipinle Eko ni ilu Abuja.  Eyin je oun ti o bani ninu ...

Read More »
Chidi Onyenekwu

Ogbe Ni Alabo Kan yin ibon pa Orere Ni ilu Enugu

Oṣiṣẹ alabo kan ti orukore unje ogbeni Chidi Onyenekwu, padanu emi e lala iro tele, nipase asise ti ikan ninu awon ti won jo unsise abo se, Ni ibamu si Ọgbẹni Ugonna Chiji Achuko ti, afi oro wa nenu wo, ...

Read More »
One dies in Mushin gang war

Eniyan Kan Ku ni Mushin Narin Awon Omo Egbe Onijagidijagan

Rogbodiyan ti o be sile larin awon omo egbe onijagidijagan, Alamutu ati Alaka ni agbegbe kan ti a un pe ni Mushin ni ilu Eko eyi ti o fa ijamba ti o mu emi eniyan kan lo si orun aaremabo, ...

Read More »
india

Agbajopo Ibinu da ija Eneya-meya si le, Eyi ti o mu emi Omokurin ka lo ni ilu ‘India’.

Ogogorun awon olugbe ti ẹya Indian ilu ibi ti Ọdọkùnrin ti kú, eyi ti won fura si wipe olo aloju oògùn, eyi ti o si fa rogbodiyan larin awon ati awon omo orilende ti ile Afirika eyin won un se ...

Read More »

Viral Video

Support Ooduarere

SUPPORT OODUARERE
Scan QR code below to Donate Bitcoin to Ooduarere
Bitcoin address:
1FN2hvx5tGG7PisyzzDoypdX37TeWa9uwb