Toju iwa re, ore mi; Ola a ma si lo n’ile eni, Ewa a si ma si l’ara enia, Olowo oni ‘nd’olosi b’o d’ola. Okun l’ola; okun n’igbi oro, Gbogbo won l’o nsi lo n’ile eni; Sugbon iwa ni m’ba ...
Read More »
Àṣà Oòduà, Asa Ibile Oòduà. Oòduà (Yoruba) je okan ninu awon eya ti o laju ju lode aye yi. Lati igba ti alaye ti daye ni won ti ni eto ati ilana to kun nipa ohun gbogbo ti won nse ni igbesi ayee won.
ayangalu Comments Off on Ewi Toni: Toju Iwa Re Ore Mi
Toju iwa re, ore mi; Ola a ma si lo n’ile eni, Ewa a si ma si l’ara enia, Olowo oni ‘nd’olosi b’o d’ola. Okun l’ola; okun n’igbi oro, Gbogbo won l’o nsi lo n’ile eni; Sugbon iwa ni m’ba ...
Read More »ayangalu Comments Off on Owó ti te àwon àpapò tí a mò sí Boko Haram tí won ń dógbón se bíi fúlàní darandaran ní ìlú Edo
NAN, Otaru ti ilè Auchi, Alhaji Aliru H. Momoh , ní ìlú Edo, ti kéde ní ojó ajé bí owó se te okòó lé mérin( 24) àwon afurasí Boko Haram tí won ń se bíi fúlàní darandaran ní agbègbè náà ...
Read More »ayangalu Comments Off on Laura Ikeji àti Ogbonaya Kanu kí omo tuntun sí inú ìdílé won ní ìlú òyìnbó (u. S).
Omo ìyá Linda Ikeji , Laura Ikeji àti oko rè Ogbonna Kanu kí omo tuntun káàbò sí ìdílé won ní ìlú òyìnbó (U. S). Linda Ikeji kéde ewu omo tuntun náà lórí èro ayélujàra (instagram), níbi tí o ti pín àwòrán ...
Read More »ayangalu Comments Off on Omo Oba Gwamnishu Harrison, tí won jígbé ,ké pé òun ń fi Nàìjíríà sílè
Olùdarí ilé-isé (CEO) ‘Behind Bar Initiative’, èyí tí ó pín àwòrán ara rè ní ibi tí ó gbé ń sunkún lórí èro ayélujàra (facebook). Ti so àsírí èròńgbà rè láti fi orílè èdè Nàìjíríà sílè lo sí ìlú òyìnbó (U. ...
Read More »ayangalu Comments Off on Èsì Ikú Tí Ó Pa Joy Odama Akékòó Odún Kejí (200l) Ti Ilé-èkó Gíga Ifáfitì Tí Ó Wà Ní Ìpínlè Cross River
Léyìn tí a gbó èsì ikú tí ó pa Joy Odama akékòó odún kejí (200l) ti ilé-èkó gíga ifáfitì tí ó wà ní ìpínlè Cross river (university of science and technology (CRUTEC)) èyí tí ó kú ikú kàyééfi léyìn ìgbà ...
Read More »ayangalu Comments Off on Gbajúgbajà Olórin, Diamond Platnumz Ti Yanjú Aáwò Tí Ó Wà Láàrin Òhun Àti Ìyá Omo Rè
Gbajúgbajà olórin ní ìlà oorùn adúláwò tí a mò si Diamond platnumz ti yanjú aáwò tí ó wà láàrin òhun àti ìyá omo rè léyìn wákàtí tí ó bá a wí fún àìso òtító . Ó pín eré oníse amóhùn ...
Read More »ayangalu Comments Off on Odomokunrin Kan Ni Orile Ede Naijiria Ati Ara Binrin Oyinbo To Sanra Mu Ki Awon Eniyan Soro
Oro to panilerin ninu itakuroso ti o wa laarin arakunrin yi ati ololufe re tele eyi ti o yan je. Arakunrin naa kunle lati beere owo owo arabinrin orobo yi fun igbeyawo.. Eyi ni lati fi ife otito han si ...
Read More »ayangalu Comments Off on Sangbafo! Won Ge Apa Ati Ori Arakunrin Kan Nitori Ija Ile Ni Ipinle Delta
Ajalu ti o n sele lowo ni amai ati umuebu ni agbegbe iwo oorun ni ijoba ibile ndokwa ti owa ni ipinle delta – o ti gba ona iburu nipa pipa odomokunrin kan ti won ge apa ati ori re ...
Read More »Lolade Comments Off on Aawọ ni Oshodi: Oluomo, Talonskibo, Harmburger Ati Oluwo.
English Version Continue after the page break
Read More »ayangalu Comments Off on Ìpínlẹ̀ Èkó ṣe Àjọyọ̀ Ìdásílẹ̀ Àádọ́ta Ọdún
Ìjọba-àpapọ̀ sọ Èkó di ìpínlẹ̀ ni àádọ́ta ọdún sẹhin. Èkó jẹ́ olú ilú fún gbogbo orilẹ̀ èdè Nigeria tẹ́lẹ̀ ki wọn tó gbe lọ si Abuja. Ìpínlẹ̀ Èkó jẹ ikan ninú ipinle mẹ́fà Yorùbá. Yorùbá ni “Èkó gba olè, ó ...
Read More »
Ọmọ Oòduà Naija Gist | News From Nigeria | Entertainment gist Nigeria|Networking|News.. Visit for Nigeria breaking news , Nigerian Movies , Naija music , Jobs In Nigeria , Naija News , Nollywood, Gist and more