Whoever this Odu is revealed to maybe during Ifá consultation, ìtènifá or Ìséfá, this person needs to offer Ebo and feed Ifa. One of the biggest problem of this person is lack of wealth. This person complains alot about not ...
Read More »Ori Eni Lawure Eni O…
Ori Eni Lawure Eni O Ori Eni Lawure Eni Mo ji lowuro mo dewo mori O Ori Eni Lawure Eni… Ki Ori wa ma sowa nu ooo… Ase Ire O! Translation One’s Spiritual/Inner head is his/her super spell(2ce) I woke ...
Read More »Eku Apere Ninu Ile Nla
Moki gbogbo apapo ojogbon awo mimo lagbaiye ninu ile nla I.K.O. nla wayi ooo Wipe :- (.KINNIHUN ORUNMILA OO.) (Ilosiwaju ishese lo jemi lo gun ooo) EJOWO OO E NPE MI SI AKIYESI Oruko mi ni iyin oluwa moje enikan ...
Read More »Orunmila O jiire l’oni o! Bi Àlà tii ji l’Ode Akure!
Okanran Meji II II II II II II I I Ifa ni: Bi a ba ti ko ni bee ni a n ki ni Bi a ba ti ki ni bee ni a n je ni Orunmila pele o ...
Read More »#Opele- Ifa ni…
Ifa ni: Opele lo yo tan lo dakun de’le A difa fun peregede tii se Yeye Ojumomo. Ojumo to mo wa loni ojumo ire ni Peregede! Ifa iwo ni Yeye Ojumomo Ojumo to mo wa loni ojumo Ajé ni Peregede ...
Read More »Aki Ijo Kinnihun Orunmila
(Atorieni Tikosun wonSe) TI ILU IBADAN LAPAPO OOO Aki gbogbo ojogbon awo mimo lapapo lagbaiye ninu ile nla I.K.O. nla wayi oo Wipe :- (KINNIHUN ORUNMILA O) (ilosiwaju ishese lo jemi lo gun o) Aki gbogbo apapo ojogbon awo mimo ...
Read More »Iwure Osu Tuntun 10/2016
Moki gbogbo ojogbon awo mimo lapapo lagbaiye ninu ile nla I.K.O. Nla wayi oo Wipe :- (.Kinnihun orunmila .O) (ilosiwaju ishese lo jemi lo gun o) (…. Ema wi tele mi wipe ….) Osu yi asan mi sowo Asan mi ...
Read More »Iwure Ojo Aje 3/10/2016
Ekaro oo se dara dara laji lowuro eni o gege bi emi na se ji oo toba ribee ejekia dupe lowo olodumare kiafi okan kan dupe lowo eleda wa ejekia bo si iwaju oke ipori wa pelu obi tabi eyi ...
Read More »Olojo Ibi Toni
Mo layo lati so fun yin wipe oni ni ojo ibi Princess Oluwakemi Morenikeji Idowu ti won je okan pataki ninu ebi Omo Yoruba Atata. Olojo ibi oni a ki yin e ku ayo oni, e o se pupo re ...
Read More »Iwure to Ori (for Good Luck)
Ka ji ni kutukutu Ka mu ohun ipin ko’pin d’Ifa fun Olomo-ajiba’re-pade Emi ni mo ji ni kutukutu ti mo f’ohun ipin ko’pin Emi ni mo ba ire pade l’ola Translation To wake up early morning And give destiny its ...
Read More »