“Mo se ileri fun orisun mi Ti I se ile yoruba, Lati je omo yoruba atata nileloko, Ati lati je omo oko, Ti ki I f’owo osi Juwe ile baba re, Lati gbe ise, asa Ati ede yoruba laruge, Nibi ...
Read More »
Àṣà Oòduà, Asa Ibile Oòduà. Oòduà (Yoruba) je okan ninu awon eya ti o laju ju lode aye yi. Lati igba ti alaye ti daye ni won ti ni eto ati ilana to kun nipa ohun gbogbo ti won nse ni igbesi ayee won.
ayangalu Comments Off on Ipade! Ipade! Ipade!
“Mo se ileri fun orisun mi Ti I se ile yoruba, Lati je omo yoruba atata nileloko, Ati lati je omo oko, Ti ki I f’owo osi Juwe ile baba re, Lati gbe ise, asa Ati ede yoruba laruge, Nibi ...
Read More »ayangalu Comments Off on Pari owe yii..
Bi ọdẹ ba ro iṣẹ, ro iya, boba pẹran ………..
Read More »ayangalu Comments Off on Ogulutu Oro Toni – 11.09.2016
Hummmmmm ile eni lati nje ekute oni dodo, Morojo oko re feni kankan mo Tori Kosi bi tise o si oni kaluku naa nfaso bo tie ni wara o si loni, wara nbo lola Woo Orewa Kosokunrin tope nile aiye ...
Read More »ayangalu Comments Off on Odu Ifa Iwure Toni Ki Bayi Wipe…
Ekaaro eyin eniyan mi, aojiire bi? Aku ise ana o, oni a sanwa sire gbogbo o ase. Odu ifa iwure toni ki bayi wipe: Òkan fìkìkìkì babalawo oladeji difa fun oladeji eyiti won nfojojumo njuwe re fun iku, won ni ...
Read More »ayangalu Comments Off on Kabiyesi Sango O!!!
ayangalu Comments Off on Yoruba Bo Won Ni Agbomojo Lomo N Moju…
Mo ki gbogbo Omo Yoruba Atata pata nile-loko ati leyin odi wipe a ku dede asiko yi, mo si ki awa ololufe eto Idile Alayo wipe e ku abo sori eto wa, eto yin, eto Ido Alayo ti ose yi. ...
Read More »ayangalu Comments Off on Idile Alayo Toni – 17.09.2016 (E Gbo Bi Atejise Na Ti Lo)
Mo ki gbogbo Omo Yoruba Atata pata nile-loko ati leyin odi wi pe a ku aseku odun emi wa yoo se pupo re laye, layo ati ni alafia ara. Mo si ki awa ololufe eto yi, wi pe e ku ...
Read More »ayangalu Comments Off on Iyawo re o, a mo eni towu oooo!
Owo idana o po ooo 5,000 pere ni oooooo
Read More »ayangalu Comments Off on Ijinle Ninu Oro Ifa Fi Ye Wa Nipa Bi Ila Se De Atelewo Wa.
Ekaaro eyin eniyan mi, aojiire bi? Ojó oni a san wa o ao ri tiwa se o ase. Gegebi awon opolopo eniyan se maa nsoro wipe “atewolabala ao meni to ko” lotito la ba ila latelewo wa sugbon imo ijinle ...
Read More »
Ọmọ Oòduà Naija Gist | News From Nigeria | Entertainment gist Nigeria|Networking|News.. Visit for Nigeria breaking news , Nigerian Movies , Naija music , Jobs In Nigeria , Naija News , Nollywood, Gist and more