Owonrin Odi I II II II II I I I Owonrin sindin sapere Adifafun Bata abufun Sango nijo won torun bowaye ebo won ni kiwon ose awon mejeji gbebo won sisebo Bata ni owonrin sindin sapere Sango ani okuu temi ...
Read More »
Àṣà Oòduà, Asa Ibile Oòduà. Oòduà (Yoruba) je okan ninu awon eya ti o laju ju lode aye yi. Lati igba ti alaye ti daye ni won ti ni eto ati ilana to kun nipa ohun gbogbo ti won nse ni igbesi ayee won.
ayangalu Comments Off on A ku Ose Sango!
Owonrin Odi I II II II II I I I Owonrin sindin sapere Adifafun Bata abufun Sango nijo won torun bowaye ebo won ni kiwon ose awon mejeji gbebo won sisebo Bata ni owonrin sindin sapere Sango ani okuu temi ...
Read More »ayangalu Comments Off on Happy Isese Day (August 20th) in advance!
Iba Olodumare Iba Ifa Olokun Asorodayo Iba Obatala Oseeremagbo Iba gbogbo Irunmole Isese Day yio ba wa layo! Aase! Happy Isese Day (August 20th) in advance!
Read More »ayangalu Comments Off on Odu Ifa Owonrinsindin/edi
| | | | | | | | | | | | Ekaaro eyin eniyan mi, aojiire bi? Aku ise ana o, eledumare yio pin ere kanwa o, ayo ojo oni koni fiwa sile o ase. Odu ifa OWONRINSINDIN/EDI ...
Read More »ayangalu Comments Off on Odu Ifa Owonrin Obara – Faniyi David Osagbami
| | | | | | | | | | | | | Ekaaro eyin eniyan mi, aojiire bi? Aku ise ana o, a si ku isimi opin ose, mo gbaladura laaro yi wipe ako ni pejopo sunkun ara ...
Read More »ayangalu Comments Off on Ori Eni Lawure Eni O – Iyalorisa Omitonade Ifawemimo
Ori Eni Lawure Eni O Ori Eni Lawure Eni Mo ji lowuro mo dewo mori O Ori Eni Lawure Eni… Ki Ori wa ma sowa nu ooo… Ase Ire O! Translation One’s Spiritual/Inner head is his/her super spell(2ce) I woke ...
Read More »ayangalu Comments Off on Owe ati Ibeere Toni – 05.08.2016
– Dabimoseda Alaisan toni ohun o je eyin(egg) ejo(snake) Ibeere Toni -nje IFE otito siwa bi tati jo mo bi?
Read More »ayangalu Comments Off on Ogulutu Oro Toni – 01.08.2016
Hummmmmm were were odunyi tun pari lo re. Humm Oya bi arare lere Wipe lati ibeere odunyi tofi di akoko tawa. Kilo ti gbese????? Hummmmmm Woo orewa Nje o mope Olohun koda o lasan bi? Maduro toraye gan oduro lasan. ...
Read More »ayangalu Comments Off on Iwure Osu Tuntun 01/08/2016
E MAA WI TELE MI : Ire ayo ni temi losu yii. Ire idunnu ni temi losu yii. Ire owo ni temi losu yii. Edumare foro mi se’yanu lose yii. Igbega ati aseyori ni temi. Osu yii yoo san mi ...
Read More »ayangalu Comments Off on A o ni jin sofin aye pelu ase Olodumare. Ase o…
Ofun saa lefun Ofun saa losun Ofun saa ni moriwo Ope yeyeye A difa fun Alagemo terekange Tii se Omo Orisa igbowuji Nitori ajeku Baba Alagemo Nitori amunku Baba Alagemo Won ni ki Alagemo losi apookun Kio lo si ilameji ...
Read More »ayangalu Comments Off on Odu Ifa Irosun Ika/Oromosunka
| | | | | | | | | | | | | Ekaaro eyin eniyan mi, aojiire bi? Aku ise ana, a sin ku isimi oni emin wa yio se pupo re laye ninu alaafia ara o ase. Odu ...
Read More »
Ọmọ Oòduà Naija Gist | News From Nigeria | Entertainment gist Nigeria|Networking|News.. Visit for Nigeria breaking news , Nigerian Movies , Naija music , Jobs In Nigeria , Naija News , Nollywood, Gist and more