Se looto nii
Read More »
Àṣà Oòduà, Asa Ibile Oòduà. Oòduà (Yoruba) je okan ninu awon eya ti o laju ju lode aye yi. Lati igba ti alaye ti daye ni won ti ni eto ati ilana to kun nipa ohun gbogbo ti won nse ni igbesi ayee won.
admin Comments Off on Awon oun marun-un te e mo nipa awon obirin
Se looto nii
Read More »admin Comments Off on Ori kini won gbe sinu obe yii?
E woju obe ke e muyan. Iyan ‘re obe e re!
Read More »admin Comments Off on Ki lo gbayi bi aso ibile wa?
Aso to fi iwa omoluabi han to si rewa loju; aso to ponni le, aso tomo le jogun lowo eni. Ninu maaki mewaa (10), meloo le fe fun baba atomo re nipa imura won?
Read More »admin Comments Off on Foto: Kini obirin le se na ?
Kini obirin le se na, to le mu oko re na bi eleyii pelu oyun ninu? Iru iwa awon odaju okunrin bayii bani lokan je gidi. Sebi o se maa ri lo ni yii?
Read More »Inu fiimu wo ni foto yii ti jade?
Read More »admin Comments Off on Alaafin Lamidi gbalejo Owa Obokun nilu Oyo
Oba Lamidi Adeyemi III, Alaafin tilu Oyo gbalejo Oba (Dr.) Adekunle Aromolaran, Owa tilu Ilesa ni aafin tilu Oyo
Read More »admin Comments Off on Sambo Dasuki wo gau! Falana setan lati gbe lo si ilejo idaran ti okeere
Agba ninu ise amofin to tun je agbejoro ti n ja fun eto omoniyan, Ogbeni Femi Falana ti seleri lati gbe oludamoran nipa eto abo fun ijoba apapo tele ri, Sambo Dasuki ati awon akegbe re ti won ka modi ...
Read More »admin Comments Off on Obatala & His Kettle Drum !
Igbin Drums are the sacred Drums of Obatala The broken poison box The broken sword Ifa divination was performed for Mobikugbe Mother of hare (Ehoro) Oriṣaala, lover of song and drum Also an elder among all oriṣas He has a ...
Read More »admin Comments Off on Post of the Day !
I never once in my life regrets ever since I started listen to voice of OLODUMARE through IFA. Is the only way to hear the true/real voice of OLODUMARE try and see.
Read More »admin Comments Off on Akasu oro Fayose: “Eni ba fori so mi, yoo fo yangayanga”
Gomina ipinle Ekiti, Ayodele Peter Fayose, ti fi da gbogbo ara ilu loju wi pe didun losan yoo so fun egbe alaburada, PDP, ninu eto idibo alaga ibile eleyii ti yoo waye lojo kokandinlogun osu kejila odun yii (19-12-15). Sugbon ...
Read More »
Ọmọ Oòduà Naija Gist | News From Nigeria | Entertainment gist Nigeria|Networking|News.. Visit for Nigeria breaking news , Nigerian Movies , Naija music , Jobs In Nigeria , Naija News , Nollywood, Gist and more