Erin ayo lenu gomina Abiola Ajimobi nigba ti won pe e lori ago wi pe o ti feyin Adewolu Ladoja janle nile ejo. Gomina Abiola Ajimobi ni ile ejo ti n risi awuyewuye eto idibo gomina ti da lare eleyii ...
Read More »
Àṣà Oòduà, Asa Ibile Oòduà. Oòduà (Yoruba) je okan ninu awon eya ti o laju ju lode aye yi. Lati igba ti alaye ti daye ni won ti ni eto ati ilana to kun nipa ohun gbogbo ti won nse ni igbesi ayee won.
admin Comments Off on Erin jade lenu Ajimobi leyin to feyin Ladoja janle nile ejo
Erin ayo lenu gomina Abiola Ajimobi nigba ti won pe e lori ago wi pe o ti feyin Adewolu Ladoja janle nile ejo. Gomina Abiola Ajimobi ni ile ejo ti n risi awuyewuye eto idibo gomina ti da lare eleyii ...
Read More »admin Comments Off on Ooni tuntun wo ilu Ile-Ife tilu-tifon
Omooba Adeyeye Enitan Ogunwusi ti wo ilu Ile-Ife fun imurasile fun iwuye re ti o waye ni kopekope yii
Read More »admin Comments Off on E wa wo ise opolo to fakiki
Ise awon asaraloge ni ki won tunrase. Sugbon nigba mi-in, won tun le baraje. Sebi bise ba se gba ni won se n se e. Ise opolo ni ise tiata, awon onitiata ni won se ise opolo. Foto: eni ti ...
Read More »admin Comments Off on Yanju Adegboyega: Ohun ti won wi ti ko koreeti”
“Nje e mo pe “oye to kan ara Iwo, o n bo wa kan ara Ede, tawon kan maa n wi yen ko koreeti? Ilu kan n be ni ka to de Ede ti won n pe “Awo”, ilu yii ...
Read More »admin Comments Off on Wahala sele ni Los Angeles lojo Satide: Rihanna fi komu lasan korin
Lojo Satide to koja yii ni CBS RADIO ranse pe Rihanna, ogbontarigi akorinbirin ile America. Ariya to waye ni Hollywood Bowl to wa ni Los Angeles ni won se lati fi se igbonlongo wi pe awon obirin le segun aisan ...
Read More »admin Comments Off on Omoge Onibadi Olokiki Ilu Amerika gbe oyun re rode: Kim Kardashian si ta lenu sibe
Joojumo loyun Kim Kardashian n ga sii. Yato si wi omobirin onibadi olokiki ilu Amerika naa kunra ju ti tele lo, ewa re si wa sibe digbi. Bakan naa ni awon imura re ko fi bee yato si awon aso ...
Read More »admin Comments Off on Orisiirisii la n ri nibi eto igbeyawo aye ode oni
Se ara eto igbeyawo ile Yoruba naa ni yii? Oko kawo le aya iyawo re nigba ti iyawo naa kawo le ori (re mi) ololufe re nita gbangba. Se bi won se n se lode oni ni yii? #YorubaDun
Read More »admin Comments Off on Iroyin Pajawiri: Olori egbe awon asewo Naijiria, Jessica Elvis ti ku
Iroyin yajo-yajo to sare wole yii lo n salaye wi pe arabirin Jessica Elvis to je olori egbe awon asewo, oninabi ile Naijiria ti rekoja lo sorun.
Read More »admin Comments Off on Asiri Tony Blair ati George Bush tu: Blair ti lo toro aforojin ni ti e
Olootu ile Biritiko nigba kan ri, Tony Blair, ti toro aforojin lowo gbogbo aye pelu bose lediapopo mo ijoba ile Amerika eleyii ti George Bush se adari fun lati fogun ja ile Iraq. Alaye yii ni Ogbeni Tony se lori ...
Read More »admin Comments Off on Foto: Davido se baba gidi fomo re
Sebi tori omo naa la se n sise… Omoomo baba olowo
Read More »
Ọmọ Oòduà Naija Gist | News From Nigeria | Entertainment gist Nigeria|Networking|News.. Visit for Nigeria breaking news , Nigerian Movies , Naija music , Jobs In Nigeria , Naija News , Nollywood, Gist and more