Ò̩pò̩ dúkìá sègbé sínú ìjàm̀bá iná ló̩jà Amu l’EkooLáti o̩wó̩ Yínká ÀlàbíEledua jowo maa so wa pelu ijamba ina to n sele lasiko eerun yii.Lojiji ni ijamba tun be yo ni oja gbaju-gbaja Amu ti o wa ni ilu Mushin ...
Read More » 
		Àṣà Oòduà, Asa Ibile Oòduà. Oòduà (Yoruba) je okan ninu awon eya ti o laju ju lode aye yi. Lati igba ti alaye ti daye ni won ti ni eto ati ilana to kun nipa ohun gbogbo ti won nse ni igbesi ayee won.
ayangalu Comments Off on Ò̩pò̩ dúkìá sègbé sínú ìjàm̀bá iná ló̩jà Amu l’Ekoo
Ò̩pò̩ dúkìá sègbé sínú ìjàm̀bá iná ló̩jà Amu l’EkooLáti o̩wó̩ Yínká ÀlàbíEledua jowo maa so wa pelu ijamba ina to n sele lasiko eerun yii.Lojiji ni ijamba tun be yo ni oja gbaju-gbaja Amu ti o wa ni ilu Mushin ...
Read More »ayangalu Comments Off on Ilé-ẹjọ́ Tó Ga Jù Ní Samuel Ortom Náà Ló Tún Jáwé Olúborí Ní Benue
Ilé-ẹjọ́ tó ga jù ní Samuel Ortom náà ló tún jáwé olúborí ní BenueLáti ọwọ Yínká Àlàbí Iroyin yajoyajo to wole bayii lo n jeri sii bi ile ejo to ga ju lo to fi ikale si ilu Abuja se ...
Read More »ayangalu Comments Off on Ìjọba Àpapọ̀ Kò Gbẹ́sẹ̀lẹ̀ Lé Owó Tó Tọ́ Sáwọn Ìjọba Ìbílẹ̀ L‘ọyọ
Lórí ọ̀rọ̀ kan tó gbà gboro kan pé àgbẹjọrò àgbà orilẹ̀-èdè Naijiria, Abubakar Malami ti pàṣẹ fún gómìnà ìpínlẹ̀ Oyo láti gba àwọn alága káńṣù ti wọ́n yọ nípò pada, Ìjọba Ọyọ ti fèsì lórí ìṣẹ̀lẹ̀ náà.
Read More »ayangalu Comments Off on Asiwaju Sí Aso̩ Lójú Eégún “Operation Àmò̩té̩kùn” Láti O̩wò̩ Yínká Àlàbí
Asiwaju Bola Ahmmed Tinubu to je asiwaju agba ninu egbe oselu APC ni gbogbo aye ti n wa kiri lati ojo ti Abubakar Malami ti ni idasile Amotekun ko ba ofin mu.
Read More »ayangalu Comments Off on Ó ju ẹnu Malami lọ láti ní ètò náà kò bófin mu
Kí ojú má ríbi, gbogbo ara lòògùn rẹ̀, èyí ló mú kí Gómìnà ipinlẹ Ọyọ, Ṣèyí Mákindé sáré tètè gba ìlú Abẹokuta lọ, láti lọ ṣèpàdé pọ̀ pẹ̀lú Olóyè Olusẹgun Ọbasanjọ.
Read More »ayangalu Comments Off on Ìdí tí nó̩ḿbà ìdánimò̩ kò fi jé̩ dandan mó̩ – Àjo̩ JAMB
Ẹ kò nílò nọńbà ìdánimọ̀ NIN fún ìdánwò àṣewọlé ọdún 2020… Àjọ JAMB Fẹ́mi Akínṣọlá Ni báyìí Àjọ tó ń rí sí ìdánwò àṣewọlé ilé ẹ̀kọ́ gíga JAMB tí kó àfàró nípa lílo nọ́mbà ìdánimọ̀ “NIN” fún ìdánwò àṣewọlé ọdún ...
Read More »ayangalu Comments Off on Ẹ kéde iye ọlọ́pàá tó gba rìbá, kí ẹ tó má a yin ra a yín… Aráàlú sọ fún iléeṣẹ́ ọlọ́pàá
Ẹ kéde iye ọlọ́pàá tó gba rìbá, kí ẹ tó má a yin ra a yín… Aráàlú sọ fún iléeṣẹ́ ọlọ́pàá Èsì àwọn ọmọ Nàìjíríà tó tẹ̀lé bí iléèṣẹ́ ọlọ́pàá ṣe yin ara rẹ̀Lórí káàdì tí wọ́n fi síta lójú ...
Read More »ayangalu Comments Off on Iyami And Ipese To Appease Iyami
The Iyami are supernatural women who have been blessed by Elodumare with a great power which can be seen in the Odu Ifa Osetua, where it is written: anyone who makes a plan by excluding from it the ideas of the women, must know that their plan is intended to fail.
Read More »ayangalu Comments Off on Transforming Ìṣẹ̀ṣe Temples, Shrines, Houses Of Worship
Women devotees live in a sanctuary that attends to both their spiritual and physical needs at the Àkòdì Òrìṣà. We train them to produce things that can be marketed. Spirituality is great and necessary. But we also have material needs—which ...
Read More »ayangalu Comments Off on M C Oluo̩mo̩ fo̩wó̩ o̩lá gbáwa lójú – NURTW
MC Oluo̩mo̩ fo̩wó̩ o̩lá gbáwa lójú – NURTWLáti o̩wó̩ Yínká ÀlàbíOro ti gbogbo ara ilu ni o ti ku regbe ti o si ti di ohun igbagbe ni o tun n rugbo ni ibere ise yii laarin Musiliu Akinsanya ati ...
Read More » Ọmọ Oòduà Naija Gist | News From Nigeria | Entertainment gist Nigeria|Networking|News.. Visit for Nigeria breaking news , Nigerian Movies , Naija music , Jobs In Nigeria , Naija News , Nollywood, Gist and more
Ọmọ Oòduà Naija Gist | News From Nigeria | Entertainment gist Nigeria|Networking|News.. Visit for Nigeria breaking news , Nigerian Movies , Naija music , Jobs In Nigeria , Naija News , Nollywood, Gist and more