Tinubu, má dàá sí ọ̀rọ̀ ìdìbò gómìnà Edo–PDP kìlọ̀ Ṣé látàrí a á sìnlú a à sìnlú yìí náà lọ̀rọ̀ wá di fàá ká já a báyìí, tí àwọn ẹgbẹ́ òṣèlú ń jùkò ọ̀rọ̀ lu ra wọn.Nífèsì padà sí n ...
Read More » 
		Àṣà Oòduà, Asa Ibile Oòduà. Oòduà (Yoruba) je okan ninu awon eya ti o laju ju lode aye yi. Lati igba ti alaye ti daye ni won ti ni eto ati ilana to kun nipa ohun gbogbo ti won nse ni igbesi ayee won.
AbubakarMuhd Comments Off on Tinubu, má dàá sí ọ̀rọ̀ ìdìbò gómìnà Edo–PDP kìlọ̀
Tinubu, má dàá sí ọ̀rọ̀ ìdìbò gómìnà Edo–PDP kìlọ̀ Ṣé látàrí a á sìnlú a à sìnlú yìí náà lọ̀rọ̀ wá di fàá ká já a báyìí, tí àwọn ẹgbẹ́ òṣèlú ń jùkò ọ̀rọ̀ lu ra wọn.Nífèsì padà sí n ...
Read More »ayangalu Comments Off on Òṣìṣẹ́ mẹ́rin bọ́ sí gbaga ọlọ́pàá lórí ikú ọ̀gá wọn tó rì sómi
Ìgbákejì Ọ̀gá Àgbà iléeṣẹ́ tó ń rí sí ọ̀rọ̀ owó orí, Price Water Coopers , PwC Nigeria , Tola Ogundipẹ ti jáde láyé. Ọjọ́ Sátidé ni wọ́n ti bẹ̀rẹ̀ sí ní wá arákùnrin náà lẹ́yìn tó wọ ọkọ̀ ojú omi ...
Read More »AbubakarMuhd Comments Off on Ọwọ́ ọlọ́pàá tẹ àwọn tó f’ọ́lé e MKO Abiola
Ọwọ́ ọlọ́pàá tẹ àwọn tó f’ọ́lé e MKO Abiola À ṣẹ kò sééyan táyé ò lé bá ṣọ̀tá, ó tún hàn pé wọ́n le bínú òkú ọ̀run , yàtọ̀ sèèyan tí wọ́n jọ ń wà láyé. À bí kín ní ...
Read More »ayangalu Comments Off on Ìjọba Nàìjíríà kéde ìlànà tuntun fún ìséde Kofi-19
Ìjọba Nàìjíríà kéde ìlànà tuntun fún ìséde Kofi-19 Ṣe àwọn àgbà bọ̀ wọ́n ní kò sí ohun kan tó le le le tí kìí padà rọ̀, ìdí nìyí tó fí jẹ́ pé, ìrọ́jú ló yẹ ẹni tí eégún bá ń ...
Read More »ayangalu Comments Off on Ìrọ̀rùn dé, Yínká Ayéfẹ́lẹ́ le è dúró kọrin báyìí
Ìrọ̀rùn dé, Yínká Ayéfẹ́lẹ́ le è dúró kọrin báyìí Ẹ̀dá tí tó bá sì wà lókè èèpẹ̀ tó ń ṣẹ̀mí, ìrètí kò pin fúnrúfẹ́ onítọ̀ùn, bẹ́ẹ̀ gẹ́lẹ́ lọ̀rọ̀ rí fún gbajúgbajà olórin jùjú n-nì, Yínká Ayéfẹ́lẹ́ bí ó ti jẹ́ ...
Read More »ayangalu Comments Off on Wọ́n ti yan adarí tuntun fún Ifásitì “Unilag”
Ó jọ bíi ẹni pé kángun kàngùn kángun ilé ẹ̀kọ́ Ifásitì ìpínlẹ̀ Èkó tí kángun síbi kan báyìí o, bí Ìròyìn tó ń tẹ̀ wá lọ́wọ́ ṣe ń fìdí rẹ̀ múlẹ̀ pé àwọn aláṣẹ Ilé ẹ̀kọ́ gíga Ifásitì Èkó, Unilag ...
Read More »ayangalu Comments Off on Sunday Shodipe tí wà láhàámọ wa– Alukoro ọlọ́pàá Ọ̀yọ́
Sunday Shodipe tí wà láhàámọ wa– Alukoro ọlọ́pàá Ọ̀yọ́ Fẹ́mi Akínṣọlá Ilé iṣẹ́ Ọlọ́pàá ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ ti sọ ọ̀rọ̀ kanranjágbọ́n afurasí Sunday Shodipe di ẹgbẹ̀rún ìsáǹsá tí wọn ò lè sá mọ́ Ọlọ́run lọ́wọ́, bí ìròyìn tó ń tẹ̀wà lọ́wọ́ ...
Read More »ayangalu Comments Off on A ti mú afurasí tó ń jẹ igbẹ níbàdàn–Ilé iṣẹ́ Ọlọ́pàá
A ti mú afurasí tó ń jẹ igbẹ níbàdàn–Ilé iṣẹ́ Ọlọ́pàá Ayé ń lọ sópin, ohun tétí ò fẹ́ ẹ̀ gbọ́ rí lojú ń rí báyìí o.Ilé iṣẹ́ ọlọ́pàá ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ ní ìwádìí ti bẹ̀rẹ̀ ní pẹrẹwu lóri ọkùnrin kan ...
Read More »ayangalu Comments Off on Bishop Oyedepo ní láti tẹ̀lé òfin tàbí kí ó dá orílèèdè tirẹ̀ sílẹ̀ – Iléesẹ́ Ààrẹ
Oludasile ile ijosinLiving Faith Church Worldwide, Bishop David Oyedepo lo ti n gbe peregi kana pelu ijoba apapo lati bii odun meloo kan seyin. Ofin lori owo ori ati amojuto awon ile-ise ati awon ile-ijosin ti ajo Company and Allied ...
Read More »baileygage505 Comments Off on Iyawo Oloju Buluu
‘Kìí ṣe tìtorí owó ni mo ṣe fẹ́ gba Risikat padá, mo ní ìfẹ́ ẹ rẹ̀ ni ‘ Wasiu Jimoh, ọkọ Risikat tó ní ojú búlúù ní Ilọrin bá BBC Yorùbá sọ̀rọ̀, ìyàwó rẹ̀ náà fèsì. Iyawo Oloju Buluu Ẹ ...
Read More » Ọmọ Oòduà Naija Gist | News From Nigeria | Entertainment gist Nigeria|Networking|News.. Visit for Nigeria breaking news , Nigerian Movies , Naija music , Jobs In Nigeria , Naija News , Nollywood, Gist and more
Ọmọ Oòduà Naija Gist | News From Nigeria | Entertainment gist Nigeria|Networking|News.. Visit for Nigeria breaking news , Nigerian Movies , Naija music , Jobs In Nigeria , Naija News , Nollywood, Gist and more