Gbajúgbajà òsèré, Omoni Oboli àti oko rè Nnamdi se ayeye odún métàdínlógún ìgbéyàwó won. Won sì pín àwòrán tipétipé won…
Read More »
Àṣà Oòduà, Asa Ibile Oòduà. Oòduà (Yoruba) je okan ninu awon eya ti o laju ju lode aye yi. Lati igba ti alaye ti daye ni won ti ni eto ati ilana to kun nipa ohun gbogbo ti won nse ni igbesi ayee won.
Awoyemi Bamimore Comments Off on Omoni àti Nnamdi Oboli se ayeye ìrántí odún métàdínlógún (17) ìgbéyàwó won pèlú àwòrán tí ó ti pé.
Gbajúgbajà òsèré, Omoni Oboli àti oko rè Nnamdi se ayeye odún métàdínlógún ìgbéyàwó won. Won sì pín àwòrán tipétipé won…
Read More »Awoyemi Bamimore Comments Off on Àwòrán kí ó tó di ojó ìgbéyàwó tí tokotayà yí yà.
Gift Clarke, èyí tí a gbó wípé ó fé fé àfésónà rè kí odún yí tó parí, ni ó pín àwòrán kí won tó se ìgbéyàwó tí ó rewà yí. Oko àti aya sì dàbí egbin…
Read More »Awoyemi Bamimore Comments Off on Ay Makun àti Aliko Dangote níbi ayeye ìgbéyàwó omo Saraki .
Ìgbéyàwó omo Saraki tí ó ti gbòde kan tí àwon òtòkùlú orílè-èdè Nàíjíríà sì péjú pésè níbè. Ay apanílèrín àti Aliko Dangote náà sì lo. Won sì jo ya àwòrán níbi ìgbéyàwó naa….
Read More »Ní ìsàlé ni àwòrán ayeye ìgbéyàwó omo Saraki tí ó n jé Olutosin Halima Saraki, omobìnrin Saraki, omo asojú ilé-ìgbìmò asòfin , Bukola Saraki tí won se ní ilé ìtura àti ìgbàlejò (Eko hotel and suites ) ìpínlé…
Read More »Awoyemi Bamimore Comments Off on Omokùnrin Amanda Ebeye se ayeye odún kan ojó ìbí rè.
Ìyá tí inú rè n dùn pín àwòrán òun àti omokúnrin rè sí orí èro ayélujára (Instagram) tí ó sì ko síbè wípé ” kú ayeye ojó ìbí rè omo Mi…..Ayé mi ….Enìkejì mi…. Eni tí ó ...
Read More »Awoyemi Bamimore Comments Off on Kí le ma se fun tí ó bá jé omo yín lásìkò yí.
Èmi ma le àpótí mo…
Read More »Awoyemi Bamimore Comments Off on Àwòrán Mompha àti àwon omobìnrin Chinese tí Hushpuppi fi èsùn kàn án wípé ó n bá won sùn.
Síwájú Hushpuppi bú òré rè tí ó so wípé kò ní owó lówó lórí èro ayélujára (Instagram). Hushpuppi fi èsùn kàn án wípé ó n bá àwon omobìnrin Chinese tí kò to sùn. Àwòrán Mompha re, pèlú àwon ...
Read More »Awoyemi Bamimore Comments Off on Àwòrán tí Aduni Ade àti omo rè okùnrin yá tí ó sì wuni .
Arewà tí ó bí omokùnrin méji ni ó pín àwòrán òhun àti ìkan lára omo rè méjì sí orí èro ayélujára (Instagram). “Won n bínú wíwà l’áyé wa Tí ó sì jé wípé àwon ni won sún mó ...
Read More »Awoyemi Bamimore Comments Off on Kàyééfì ò ní yé selè, odóbìnrin kan ni ó ya tàtúù ojú Wizkid àti lógò starboy sí èyìn rè.
Òkan lára àwon olólùfé Wizkid ni ó ya tàtúù ojú Wizkid àti logo starboy sí èyìn rè…
Read More »Awoyemi Bamimore Comments Off on Asojú ilé-ìgbìmò asòfin Ademola Adeleke, ni a rí tí ó n jó pèlú àwon arewà.
Àwòrán ègbón Davido, asojú ilé-ìgbìmò asòfin ní bi tí ó ti n jó láàrin àwon arewà…
Read More »
Ọmọ Oòduà Naija Gist | News From Nigeria | Entertainment gist Nigeria|Networking|News.. Visit for Nigeria breaking news , Nigerian Movies , Naija music , Jobs In Nigeria , Naija News , Nollywood, Gist and more