Aki gbogbo eyin ojogbon awo mimo lagbaiye ninu ILE NLA I.K.O. nla wayi o Wipe :- (.KINNIHUN ORUNMILA.) Iye eni kokan wa koni ra ooo Ejowo ooo Ti obinrin basun tioba la ala wipe ohun pade were loju orun to ...
Read More »
Àṣà Oòduà, Asa Ibile Oòduà. Oòduà (Yoruba) je okan ninu awon eya ti o laju ju lode aye yi. Lati igba ti alaye ti daye ni won ti ni eto ati ilana to kun nipa ohun gbogbo ti won nse ni igbesi ayee won.
ayangalu Comments Off on Ejowo O Eyin Ojogbon!! Efun Wa Ni Imoran Lori Ala Yi O
Aki gbogbo eyin ojogbon awo mimo lagbaiye ninu ILE NLA I.K.O. nla wayi o Wipe :- (.KINNIHUN ORUNMILA.) Iye eni kokan wa koni ra ooo Ejowo ooo Ti obinrin basun tioba la ala wipe ohun pade were loju orun to ...
Read More »ayangalu Comments Off on Iwure Ojo Eti
Moki gbogbo ojogbon awo mimo lagbaiye ninu ile nla wayi o Wipe :- (.KINNIHUN ORUNMILA OO.) (.Ilosiwaju Ishese Lo Jemi Lo Gun o.) Mofi asikoyi gba ni iwure fun gbogbo eda omo adariwuhun tioba lefi atejishe ee se (Aseee) labee ...
Read More »ayangalu Comments Off on Ifa olokun adore dayo aso oro gbogbo wa di ayo ooo.
Ase !
Read More »ayangalu Comments Off on Odo Iwoyi – E Gbo Bi Atejise Toni Ti Lo
Mo ki gbogbo Omo Yoruba Atata pata nile-loko ati leyin odi wi pe a ku dede asiko yi, mo si ki awa ololufe eto Odo Iwoyi wi pe e ku abo sori eto wa, eto yin, eto Odo Iwoyi ti ...
Read More »ayangalu Comments Off on Isebo ni isegun baa ti waye pa a ri, la a
ri ………Ohun gbogbo lowo ori eni. Ori mi ma pada leyin mi. Ojumo Ire o!
Read More »ayangalu Comments Off on Ose tu’a
ko-mi-koro awo Ewi l’Addo Orun koko-ko awo Ijesa m’Okun Alakan nigbo ‘do t’eye ifá kerekere-kere adi’a fun Igba Irunmole ajikotun obu okan fun Igba Imole ajikosi alukin fun Orunmila nijo ti won ti Isalu orun bo wa Isalu aiye Eledumare ...
Read More »ayangalu Comments Off on APINTANBI
Ekaaro eyin eniyan mi, aojiire bi? Aku ise ana o, a si tun Ku isimi opin ose eledumare koni jeki a fi eleyi se asemo o ase. Laaro yi mo fe so die nipa oro APINTANBI ti awon opuro ati ...
Read More »ayangalu Comments Off on Isu Oro bale ro pee…
A da fun eji, ti o ma bowo fun iko Odidere, won ni ko kara nile, Ebo ni ko mu se. Ojo o ni ro ko pa ina iko Odidere, Iko Odidere d’Orisa. Ni Agbara Olodumare ati oruko Orunmila, Gbogbo ...
Read More »ayangalu Comments Off on Ibi ti ilę ti fę !
Oju Opon Ifa.
Read More »ayangalu Comments Off on Otura Oriko, wa lo ree silekun ire temi fun mi! Aase!
Hoje também é dia de propiciarmos Olokun. Que a força e o Ase de Olokun abra as portas do progresso e da prosperidade a nossa família criando condições para que todos os obstáculos sejam retirados de nosso caminho. Ikan lowo ...
Read More »
Ọmọ Oòduà Naija Gist | News From Nigeria | Entertainment gist Nigeria|Networking|News.. Visit for Nigeria breaking news , Nigerian Movies , Naija music , Jobs In Nigeria , Naija News , Nollywood, Gist and more