A kú àmójúbà *Osù Ebibi (May) tuntun.* Osù ìségun àséwolè ni yóò jé. A kò níí se gégé ibi, béè ni ìkònà burúkú kò níí kò wá. Nínú Osù yìí, a ó ségun òtá ilé àti tòde, a ó réyìn ...
Read More »
Awoyemi Bamimore Comments Off on A kú àmójúbà *Osù Ebibi (May) tuntun.
A kú àmójúbà *Osù Ebibi (May) tuntun.* Osù ìségun àséwolè ni yóò jé. A kò níí se gégé ibi, béè ni ìkònà burúkú kò níí kò wá. Nínú Osù yìí, a ó ségun òtá ilé àti tòde, a ó réyìn ...
Read More »Awoyemi Bamimore Comments Off on Toolz pèlú àwon tí won se àseyege ní BBnaija ti odún yí, Miracle, Nina, Cee-c Alex àti Tobi.
Àwon ará ilé télè ti BBnaija tí a mò sí Nina, Alex, Cee-c Tobi àti Miracle ni won ti ya àwòrán pèlú asojú beat FM, Toolz lóòní gégé bí won se bèrè ìrìn àjò won léyìn ìgbélé won.
Read More »Awoyemi Bamimore Comments Off on Omokùnrin Ronke Oshodi Oke, Richmond se ayeye odún kàrún ojó ìbí rè.
Ní ìsàlè ni Àwòrán ayeye ojó ìbí Richmond, omokùnrin gbajúgbajà Òsèré orí ìtàgé tí a mò sí Ibironke Ojo Anthony, tí a mò sí Ronke Oshodi Oke. Omokùnrin tí ó rewà, tí ó se ayeye odún kàrún ojó ìbí rè, ...
Read More »Awoyemi Bamimore Comments Off on ogún-l’ógbòn àwon omo léyìn egbé òsèlú APC ni won ti kí Ààre orílè èdè yí tí a mò sí Buhari káàbò sí ìpínlè Bauchi.
Ogún-l’ógbòn àwon omo léyìn egbé APC ni ó ti kí Ààre Buhari káàbò sí ìpínlè Bauchi. Bauchi tí ó jé òkan Lára àwon gbòógì tí ó máa n gba àlejò Buhari láti ìgbà tí ó ti di Ààre .
Read More »Awoyemi Bamimore Comments Off on Davido ti pín àwòrán tàtúù míràn tí ó yà.
Láìpé yí ni Davido pín sí orí èro ayélujára tí a mò sí instagram láti pín àwòrán àti ìtàn ti tàtúù tí ó sèsè yà sí apá tí ó pè ní “30BG” kí ó tó di wípé ó fé se ...
Read More »Awoyemi Bamimore Comments Off on Cee-c pèlú Toolz àti Yaw.
Ará ilé télè ti BBnaija tí a mò sí Cee-c ti ya àwòrán pèlú Yaw ti Wazobia FM àti Toolz ti Beat FM lénìí nígbà tí won se àbèwò sí won.
Read More »ayangalu Comments Off on Ifa Olokun
Let us read an article on PRIESTHOOD 1. Oluwo: This is a man who has studied and practiced Ifa as a priest for many many years and has not only seen Orisa Odu but owns Orisa Odu (Olodu: owner of ...
Read More »Awoyemi Bamimore Comments Off on Omobìnrin tí won ti ń wá láti ojó mélòó séyìn, èyí tí ó fi ilé-èkó sílè láti tèlé Òdókùnrin kan ní ìpínlè Delta.
Àwon ebí akékòó bìnrin kékeré tí ó sonù láti bí ojó mélòó séyìn ni a ti gbó wípé arákùnrin kan ni ó wá gbe ní ilé-èkó léyìn isé òòjó náà . Omobìnrin tí ó jé akékòó ní ilé-èkó Okpe grammar ...
Read More »Awoyemi Bamimore Comments Off on Ilé-ìwòsàn àwon ará Sokoto .
Ilé-ìwòsàn àwon ará Sokoto . Ìyá yí pọ̀ Ó ju omi òkun lọ Èdùmàrè Ìwọ tó o dá Ráábí aláṣọ Dákun má gbàgbé Ráábí eléwé Èdùmàrè ṣàánú mi Iná tó ń jó tálákà ní Nàìjíríà Ó dájú pé ó ju ...
Read More »
Ọmọ Oòduà Naija Gist | News From Nigeria | Entertainment gist Nigeria|Networking|News.. Visit for Nigeria breaking news , Nigerian Movies , Naija music , Jobs In Nigeria , Naija News , Nollywood, Gist and more