Gómìnà ìpínlè Ondo, Akeredolu lo bá Gómìnà ìpínlè Edo se àjoyò odún kan tí ó dé ipò ní pápá Samuel Ogbemedia, Benin city.
Read More »Ààre Buhari ní ìpínlè Anambra fún ìpolongo Dr. Tony Nwoye fún àwon omo egbé APC.
Ààre Buhari ní ìpínlè Anambra fún ìpolongo Dr. Tony Nwoye fún àwon omo egbé APC.
Read More »Regina Daniel rewà ó sì dàbí àgbàlagbà níbi àwòrán tuntun tí ó sèsè yà.
Òdóbìnrin òsèré yí, Regina Daniel ti gbe lo sí orí ìtàn èro ayélujára (insta-stories) láti pín àwòrán tí ó ti yàtò yí.
Read More »Sandra Okagbue ya orúko flavour “Chinedu” sí owó rè .
Ìyá omo olórin flavour, Sandra tàtúù orúko rè “Chinedu” sí apá .
Read More »Ajá mi , pitbull pa Àntà tí ó n sólé ,obè ti délè oo.
Èrín pa mí, ajá mi, pitbull pa á lónìí , ta ló fé?
Read More »Àwòrán kí ó tó di ojó ìgbéyàwó tí won yà nínú omi adágún.
Odára àbí kò dára?
Read More »Ìjàmbá okò tírélà tí ó selè tí ó sì se òpò èèyàn lese ní Gombe.
Èyí ni ìsèlè tí ó selè láìpé ní ojó kejìlá osù kokànlá odún yí ní Gombe ní ìpínlè Gombe tí tírélà fà . lóòtó kò sí eni tí ó kú, sùgbón òpò ni ó se Lése gan. A ...
Read More »Akpororo àti ìyàwó rè Josephine Ijeoma Onuabughuchi se ayeye odún kejì ìgbéyàwó won.
Adérìnpòsónú, Akpororo àti ìyàwó rè Josephine se ayeye odún kejì ìgbéyàwó won.
Read More »Ay lo kí Gómìnà Okorocha , ère ti e náà n bò lónà, àwon olólùfé rè ni ó so béè.
Báyìí ni adérìnpòsónú AY tí ó sèsè dé láti Dubai fún ìsinmi pín àwòrán òun àti Gómìnà ìpínlè Imo, Rochas Okorocha nígbà tí ó lo ki n’ílé, tí àwon olólùfé rè sì so wípé ère ti è náà kò ...
Read More »Àwòrán olópàá tí ó n só Afárá Apogbon (Apogbon Bridge).
Wón ti so síwájú télè wípé àwon olópàá Nàíjíríà n sisé takuntakun láti só agbègbè Apogbon bridge tí a mò fún àwon dánàdánà.
Read More »