Home / Art (page 133)

Art

ejiobge

Odu Ifa Ejiogbe: Iwure that can help to gain Wealth, Prosperity, love and favour

In this article i will explain in detail ifa daily or occasional iwure (prayer or spells) that can be use by any body to gain Wealth And Prosperity and love and favour from people in their life pursuit. When ever ...

Read More »
Yorùbá spirituality

“To be a great priest in Yorùbá spirituality, you must be truthful and Honest”

S’òtító s’òtító S’òdodo S’òdodo Ení bá s’òtító n’imolè ó gbè Be truthful Be honest Only those who are truthful will be favored by the Imole. You also need to be patient because : Ìrin baba wa, ìrìn Èrà ni Ení ...

Read More »
Dbanj

Àsírí sèsè tú sí won lówó wípé ilé-isé mi ní iye owó tí ó tó Dólà lónà ogóòrun Mílíònù ($100 million) -D’banj.

Kokomaster tí a tún mò sí D’banj le sèsè di òsèré tí ó lówó jù ní ilè adúláwò (Africa). Olórin tí ó sì jé baba omo kan sèsè gbe sí orí èro ayélujàra (instagram) rè pé Cream platform tí ó ...

Read More »
gassi

Gáàsì bú gbàmù ní Cross river tí ó sì pa èèyàn méji, tí ó fa ìpalára fún àwon mérin nínú ebí.

Àwon omo ebí mérin ti igbákejì adarí kíko eré ìdárayá ní orílè èdè Nàìjíríà ” Vice President of Sport Association (SWAN), Eddie Bekom tí a gbà sí ilé-ìwòsàn léyìn ìgbà tí gáàsì tí wón fi ń dáná bú gbàmù láti ...

Read More »
General Yakubu

Yakubu Gowon lo kí Shehu Shagari. 

Olórí ìpínlè télè (former head of state) General Yakubu Gowon lo kí Ààre ti télè Shehu Shagari ní ilé rè ní Sokoto. Gómìnà Tambuwal sìn-ín lo pèlú Olórí àlùfáà Ìjo Catholic ti Sokoto,  Bishop Matthew Hassan kukan àti àwon ènìyàn ...

Read More »
Annie Idibia

Annie Idibia da padà fún olùtèlé rè tí ó pè é ní omobìnrin tó “wor wor “.

Annie Idibia fi àwòrán yí sí orí èro ayélujàra rè (instagram) tí ó rò wípé kò rewà  pè é ní omobìnrin tó ” wor wor ” . Ìyá omo méji tí òhun náà sì da padà fun pé :bí ìyá ...

Read More »
falz nice

Falz àti 9ice je oúnje alé papò (àwòrán, fídíò).

Falz ti fi èsì àìgbó ra eni ye hàn láàrin òun àti 9ice nígbà tí òpò rò wípé 9ice ni ó ń báwí nígbà tí ó ń gba àwon olórin ní ìmòràn kí won má fi Orin yin àwon gbájúè ...

Read More »
Olubadan

Olúbàdàn kìlò kí won má se jàgídíjàgan bí odún egúngún se fé bèrè.

Gégé bí odún egúngún odoodún se ma bèrè l’óla, ojó ajé, ní ìlú Ibadan, ní ìpínlè Oyo, Olúbàdàn ti ilè Ibadan, oba Saliu Akanmu Adetunji ti pè fún àláfíà láti òdò àwon eléégún àti àwon tí ó ń tèle tí ...

Read More »
Ewedu

Àwòrán láti ìlú olómìnira kan tí a mò sí Ewédú àti ìgbálè

Àwòrán láti owó omo oòduà rere. Àwòrán láti ìlú olómìnira kan tí a mò sí Ewédú àti ìgbálè (a fé béè, èrín yakata). Ta ló tún n’ìfé àwòrán láti ìjìnlè ìlú yorùba? N’ísàlè ni àwòrán àjò lo sí ìlú Iseyin ...

Read More »
trump

Hundreds of artists mock Trump in Tehran cartoon competition

Read More »

Viral Video

Support Ooduarere

SUPPORT OODUARERE
Scan QR code below to Donate Bitcoin to Ooduarere
Bitcoin address:
1FN2hvx5tGG7PisyzzDoypdX37TeWa9uwb