Kabirat Kafidipe lori eto Gbajumo Osere
Afeez Eniola lori eto Gbajumo Osere
Ogoji (40) eniyan n ja raburabu fun ipo gomina nipinle Ondo
Awon eniyan bi ogoji (40) lapapo ni won ti fi ife han bayii lati dije fun ipo gomina ipinle Ondo eleyii ti yoo waye ninu odun yii. Ninu egbe oselu All Progressives Congress (APC), ogbon eniyan ni won ti nawo ...
Read More »Jegudujera: EFCC tun ti gbe ebi Alison-Madueke niluu Abuja
Awon Yooba bo, won ni tina ko ba tan laso, eje ki i tan leekanna. Awon ajo ti n gbogun ti iwa jegudujera ati sise owo ilu mokunmokun, EFCC, ti gbe arakunrin Donald Chidi Amamgbo to je okan lara ebi ...
Read More »Olajumoke omo oniburedi
Opolopo ni i pokiki Olajumoke Orisaguna omo oniburedi gege bi oloriire ti Edumare da lola ojiji pelu bo se se alabapada agbaoje ayaworan ati olorin ti n je TY Bello. Laaarin iseju kan, omo oniburedi di orekelewa oba onise oge. ...
Read More »Igbeyawo Ooni Ile-Ife fo yangayanga?
*Oba Ogunwusi n mura lati se igbeyawo tuntun Lose to koja ni awon aheso oro kan be sile nigboro eleyii to ti bere si ni mu awuyewuye lowo bayii. Lara awon oro naa ni eyi ti n wi pe, ...
Read More »Fayose setan lati ya awon osise lowo ra moto nipinle Ekit
“Ilaji owo osu won nijoba yoo ma yo fi san gbese naa” -Komisanna isuna owo Gomina Ayodele Fayose ti yanda owo to le ni igba milionu owo naira (N236,860,000) gege bi owo ti won ya soto lati ya awon osise ...
Read More »Gomina ipinle Kwara ti da Jelili oniso lola
*Femi Adebayo n wonu oselu lo diedie Nibayii, gomina ipinle Kwara, Abdulfatah Ahmed, ti yan ogbontarigi onisetiata, Femi Adebayo, gege bi oluranlowo pataki nipa ise ona, asa ati irinajo-afe (Special Assistant on Arts, Culture and Tourism). Osere ti inagije re ...
Read More »Kootu fi leta iku le Rev. King lowo
*Won ni ki won yegi fun un leyin to pa omo ijo re Reverend King Opin irin ajo ti de ba Rev. Chukwuemeka Ezeugo ti inagije re n je Reverend King nigba ti ile ejo to gaju yan-anyan, Supreme Court, ...
Read More »