Home / Art (page 232)

Art

mercy

Mercy Aigbe alaso oge pade Toke Makinwa

Awon Yoruba bo, won ni tode-tode ni i se alaso tuntun. Joojumo ni Mercy n sodun, Mercy Aigbe alaso oge.  Mercy tun pade Toke, sorosoro ori redio ati telifisan ti oun naa feran oge lagbo ariya.

Read More »
Maheeda

Maheeda di Pasito oloro itunnu

Kosi eni ti Olorun ko le fi owo to lokan. Maheeda, okan ninu awon olorin ile Naijiria, ti ma n bora sile nihoho tele ti wa di eni ti n gba awon eniyan niyanju bayii pelu oro itunnu ti n ...

Read More »
dayo amusa

Dayo Amusa ti pada senu ise

Dayo Amusa wa lara awon ero Mecca odun yii pelu awon akegbe re bi Fathia Balogun ni won jo goke arafa papo. Igba ti won de ni won di Alaaja tuntun. Sugbon bayii, Dayo ti pade sidi ise oojo re nibi ...

Read More »

Donald Duke se afihan iwa omoluabi ati irele

Read More »

Eleleture lati owo Akeem Lasisi

  Eyi ni fidio orin ewi lati owo Akeem Lasisi ti won pe akole re ni ELELETURE

Read More »
edumare

Somi Edumare lati owo Edaoto

Odun lo sopin, eni Edua Oke pamo nikan lo yege. Sugbon nipa temi ati awon ololufe mi, a ko ni padanu enikeni lase Eledumare. Ase  Lori eyi ni i ti ma fi yin sile lati je igbadun orin Edaoto to ...

Read More »

Ika eniyan wo lo yo oju Ibrahim sa lo?

Okunrin olokada kan ti won pe oruko re ni Ibrahim ni won sadeede ba oku re loju titi laaaro yii ni agbegbe Alaba Suru to wa loju ona masose Badagry niluu Eko. Igba ti won yoo ye okunrin naa wo, ...

Read More »
davido

London, e ku amojuba Omo Baba Olowo

Davido ti se afihan foto re lenu irin ajo re silu London. Ninu atejade yii ni Omo Baba Olowo ti n so wi pe oun ti n sun mo ilu London. Eyin ara London, se e ti wa ni imurasi?

Read More »

Ojo ibi Fayose: E wo ohun ti awon tisa fi da lola

Gomina Ayodele Fayose se ayeye ojo ibi odun marunlelaadota (55) lonii ni Ipinle Ekiti. Akara oyinbo yii ni awon tisa fi da lola.

Read More »

Ohun te e ma se ti e ba fe ki irun yin gun daada

Fun awon omoge iwoyii ti won fe nirun gigun, ti yoo dudu kirimi ti yoo si ma dan bi koroshin, ti irun naa kosi ni maa ja butebute bi owu, ogun re niyii to daju bi ada. E wa ewe ...

Read More »

VI

Viral Video

Support Ooduarere

SUPPORT OODUARERE
Scan QR code below to Donate Bitcoin to Ooduarere
Bitcoin address:
1FN2hvx5tGG7PisyzzDoypdX37TeWa9uwb