Osu kewaa odun 2007 ni awon afura si kan gege bi agbanipa bere si ni rojo ibon fun Innocent Idibia ni ibudoko Cele to wa loju ona masose Oshodi si Apapa to wa niluu Eko. Sugbon gege bi Ayinla Omowura ...
Read More »E Wa Wo Ohun Ti Won Se Fun Ole Ti Won Mu N’Ikeja
Ole ti won mu ni agbegbe Ikeja ni yii losan-an ana. Awon eniyan se idajo owo won fun-un lai duro de awon olopaa. Nje o dara ki a maa se idajo owo wa fun awon odaran tabi ki a maa ...
Read More »Aare Ilu South Africa Ti Sofin Lati Maa Sami Si Oju Ara Awon To Ba Ni Kokoro HIV
Aare ilu South Africa, Jocob Zuma, ti fi owo si abadofin lati maa sami si egbe kan oju ara awon ti won ba ni kokoro HIV lara. Won ni nipa sise eleyii, yoo mu adinku ba awon eniyan ti won ...
Read More »Video: Basketmouth’s Drawing Painting By Ayeola Ayodeji
Portrait of basket painted by a talented Omo oodua Rere.. See more pics bellow.
Read More »Yeepa! Ki le yii?
O Dabi Eni Wi Pe Inu Osupa Ni Maanu Yii Ti Wa
Read More »E Wa Wo Ohun Ti Omokekere Yii Da Lara: Eleyii Koja Afenu So
Lara awon iroyin wa to ti jade tele, awon iroyin lori ate Olayemi Oniroyin, mo se lalaye wi pe Edua Oke ko da ile Adulawo gege bi ibugbe awon otosi ati alaini; awon olori wa lo so ilu wa di ...
Read More »Omo Naijeria Setan Lati Dije Fun Ipo Aare Orileede Spain
Ko to di wi pe ma kan lu agbami oselu ti n gbona felifeli bayii ni ilu Spain, nibi ti Arabirin Helen Mukoro to je omo ipinle Delta lati orileede Naijeria ti setan lati dije fun ipo aare orileede Spain, ...
Read More »E Wo Ohun Ti Awon Omo Ile Igbimo Asofin Se Lodun 1962
Awon omo ile igbimo asofin Nigeria ti n foganna lojo to ti pe, ohun ti won se ni yii lodun 1962 nigba rogbodiyan Western Region. Orisun
Read More »Yomi Fash – Lanso N Jaye Oloba Niluu Côte d’Ivoire
YOMI FASH – LANSO Orisun +Wale Ojo-Lanre
Read More »Top 4 Exciting Things About The Fulanis
The Fulanis are amazing people with a rich heritage. The familiar picture of a man from this tribe wielding a stick fending for his priceless cow is a picture that everyone can relate with. This culture of cow rearing is ...
Read More »