Ìṣẹ parí fún òṣìṣẹ́ tó bá gbé àṣírí Ìjọba jáde lọ́nà àìtọ́—Ìjọba àpapọ̀ Ṣé àwọn àgbà bọ̀ wọ́n ní, ìlú tí kò sófin, ẹ̀sẹ̀ kò sí níbẹ̀, gẹ́lẹ́ bẹ́ẹ̀ ni ọ̀rọ̀ Orílẹ̀ yìí dà báyìí, bí Ìjọba àpapọ̀ se ni ...
Read More »Àjo̩ NCDC mú mé̩ta nínú oògùn ìbíle̩ fún ìwòsàn covid-19
Àjo̩ NCDC mú mé̩ta nínú oògùn ìbíle̩ fún ìwòsàn covid-19Yínká Àlàbí Ajakale arun ti gbogbo eniyan ro pe ko ni pe fi orileede yii sile, lo ti ko ti ko lo mo yii. Eyi lo wa bere si ni ko ...
Read More »Àwo̩n aké̩kò̩ó̩ máa wo̩lé láìpé̩
Àwo̩n aké̩kò̩ó̩ máa wo̩lé láìpé̩ Gbogbo igbiyanju ni awon ajo eto eko ti wa ninu awon ajo NCDC n se bayii lati le je ki awon akekoo wole eko won. Oro arun coronavirus yii ti su gbogbo aye. Ile ti ...
Read More »Èsì àyẹ̀wò tuntun Nàìjíríà fihàn pé “313” èèyàn ti gbàlejò Kofi 19 …àjọ NCDC
Èsì àyẹ̀wò tuntun Nàìjíríà fihàn pé “313” èèyàn ti gbàlejò Kofi 19 …àjọ NCDC À fi kí á bẹ Ọlọ́run kó bá wa dásí ọ̀rọ̀ àjàkálẹ̀ àrùn ajániláyà pàtì yìí, bí àwọn tó ní kòrónáfairọ̀ọ̀sì ní Nàìjíríà ti ń peléke ...
Read More »Ebo – The weapon of all true traditionalist.
Ebo is powerfulEbo is prayerEbo solves the unseen problemsEbo helps prevent tribulationsEbo cleanse my soulIt makes me feel completeEbo doesn’t require human partEbo is pureEbo is the key I have used Àkùko to offer Ebo for victoryI have used Etù ...
Read More »Ààrẹ Buhari dijú lé Ọ̀gá Àjọ NECO àti àwọn mẹ́rin mìíràn tó jàjẹbánu
Ààrẹ Buhari dijú lé Ọ̀gá Àjọ NECO àti àwọn mẹ́rin mìíràn tó jàjẹbánu Ààrẹ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, Muhammadu Buhari ti fi ọwọ́ òṣì júwe ilé fún adarí àjọ elétò ìdánwò àṣekágbá ti girama, NECO àti àwọn mẹ́rin mìíràn lórí ẹ̀sùn pé ...
Read More »Ọ̀daràn kan fi tipá wọ ààfin Ọ̀ọni ilé ifẹ̀
Ọ̀daràn kan fi tipá wọ ààfin Ọ̀ọni ilé ifẹ̀ A kìí gbélé ẹni ká fi ọrùn rọ́ ni a ti ń gbọ́ tipẹ́ tipẹ́, sùgbọ́n kín wá ni ká ti pe tirúfẹ́ ìṣẹ̀lẹ̀ ajániláyà yìí tó wáyé ní ààfin Ọọ̀nirìṣà ...
Read More »Ọmọọsẹ́ tó súnmọ́ mi jù lọ satọ́nà bí wọ́n se jí ìbejì mi gbé — Akewugbagold
Ọmọọsẹ́ tó súnmọ́ mi jù lọ satọ́nà bí wọ́n se jí ìbejì mi gbé — Akewugbagold Ṣé wọ́n ní olè kò ní jàgbà, kó má kó fìrí, bẹ́ẹ̀ bíkú ilé ò pani,yóó sòro díẹ̀ kí kú tòde pààyàn . Ọ̀rọ̀ ...
Read More »Èèyàn ẹgbẹ̀rún kan àti irínwó dín mẹ́fà bá Kofi 19 rìn l’Amẹ́ríkà lópin ọ̀sẹ̀.
Èèyàn ẹgbẹ̀rún kan àti irínwó dín mẹ́fà bá Kofi 19 rìn l’Amẹ́ríkà lópin ọ̀sẹ̀. À fi kí á bẹ Ọlọ́run kó báwa dáwọ́ ibi dúró nílẹ̀ yìí àti lókèèrè to rí igbi gbogbo la lẹ́ni sí lórílẹ̀.Gbogbo ìgbà ni àjàkálẹ̀ ...
Read More »Iléèṣẹ́ ọlọ́pàá ti ṣe àfihàn àwọn afurasí tó jí ìbejì Akeugbagold gbé ní ìlú Ìbàdàn
Iléèṣẹ́ ọlọ́pàá ti ṣe àfihàn àwọn afurasí tó jí ìbejì Akeugbagold gbé ní ìlú Ìbàdàn Àwọn àgbà bọ̀ wọ́n ní, àṣẹgbé kan kò sí, àsepamọ́ ló wà.Ni báyìí, kélé òfin ti mú àwọn ọ̀daràn tó jí àwọn ìbejì Alhaji Taofẹẹq ...
Read More »