Ìjọba àpapọ̀ ti pàṣẹ pé kí wọ́n tú olùbádámọràn lóri ètò ààbò Sambo Dasuki àti agbétẹrù Revolution Now Omoyele Sowore silẹ̀ nínú àhámọ́.
Read More »
ayangalu Comments Off on Mo ti pàṣẹ fún àjọ DSS láti tẹ̀lé àṣẹ ilé ẹjọ́….Abubakar Malami
Ìjọba àpapọ̀ ti pàṣẹ pé kí wọ́n tú olùbádámọràn lóri ètò ààbò Sambo Dasuki àti agbétẹrù Revolution Now Omoyele Sowore silẹ̀ nínú àhámọ́.
Read More »ayangalu Comments Off on #EsuIsNotSatan: Èşù no es el Diablo.
Ẹ̀là mo yìn bọrú.Ẹ̀là mo yìn bọyè.Ẹ̀là mo yìn bọ’ṣíṣẹ. Èşù no es el Diablo. Òlódumare y todos los Irunmoles les bendigan, que Èşù Òdàrà les proteja y lleve a sus hogares todo tipo de Bendiciones, Oluwo Ifá’Olofa Fá’nimoko Idin ...
Read More »ayangalu Comments Off on Ìjọba àpapọ̀ f’ẹ́ já iná mànàmáná orílẹ̀èdè Togo àti Benin Republic nítorí gbèsè $7m
Ìjọba àpapọ̀ f’ẹ́ já iná mànàmáná orílẹ̀èdè Togo àti Benin Republic nítorí gbèsè $7m Ariwo t’íjọba àpapọ̀ Nàìjíríà ń pa lé àwọn tó jẹ ẹ́ ni gbèsè owó iná nìyí báyìí o. Ṣùgbọ́n lọ́tẹ̀ yìí kìí ṣe àwọn ọmọ orílẹ̀-èdè ...
Read More »ayangalu Comments Off on Ó di láyéláyé pọngbá ! Àlàbí Yellow ,àgbà òṣèré re’bi àgbà á rè
Ó di láéláé pọngbá ! Àlàbí Yellow ,àgbà òṣèré re’bi àgbà á rè Gbajúgbajà òṣèré Samuel Akinpẹlu tí gbogbo ènìyàn mọ̀ sí Àlàbí Yellow ti jẹ́ Ẹlẹ́dàá nípè. Akọni tí à ń perí yìí jẹ́ òṣèré tí àwọn èèyàn kò ...
Read More »ayangalu Comments Off on Éèpà Òòsà: Òòsa éèpà
Today is Monday, Ojó Ajé(day of expectation of money), OBATALA DAY.Yorubas would say, “Àrà ňbádá owó ni ò jé” meaning, “I could perform wonders if not for unavailability of money” Never give up trying to have good life. With Obatala, ...
Read More »ayangalu Comments Off on Àlùfá tọ́ bá ọmọ ọdún méje sùn, wẹ̀wọ̀n ọdún Márùn- ún ní ìpínlẹ̀ Ekiti
Ọjọ́ gbogbo n t’olè, ọjọ́ kan n t’olóhun.Ìjọba ìpínlẹ̀ Ekiti tífìtàn balẹ̀ bí wọ́n ṣe jẹ́ ìpínlẹ̀ àkọ́kọ́ tí yóò bẹ̀rẹ̀ láti máa dárúkọ ọ̀daràn afipá bánilòpọ̀ hàn àti láti máa dójú tì wọ́n. Gómìnà ìpínlẹ̀ náà Kayode Fayemi gbé ...
Read More »ayangalu Comments Off on Ìdí tí a fi yọ Donald Trump nípò Ààrẹ
Alágbára ayé,alágbára ayé,a sè a ṣẹ̀ má lù kan, Ọlọ́run o tíì da sí dúníyàn .Bí nǹkan se n lọ yìí, Donald Trump ni Ààrẹ orílẹ̀èdè Amẹ́ríkà kẹta nínú ìtàn tí ọ̀bẹ yóó bá ń dìí láti ọ̀dọ̀ àwọn Ilé ...
Read More »ayangalu Comments Off on Kò sí ilé tàbí só̩ò̩bù tí a kò le fo̩ láti ké̩rù òfin – Àjo̩ Customs
Awon ajo asobode ile Nigeria ti gbogbo eniyan mo si Customs ni won n ba awon oniroyin soro ni ipinle Adamawa pe, ko si ile tabi soobu ti awon ko le ja tabi fo ti o ba ye.Won ni gbogbo ...
Read More »ayangalu Comments Off on Àsíá pupa dá ìjayà sílè̩ l’Ekiti
Àsíá pupa dá ìjayà sílè̩ l’EkitiYinka AlabiIdaji oni ojo kokanlelogun, osu kejila odun yii ni awon ara ilu Orin Ekiti dede de oko ti won ba Asia pupa to tumo si wi pe, ki awon ara agbegbe naa ma se ...
Read More »ayangalu Comments Off on Odu Ifa: “Irente gbe” cast for today’s Ose Ifa
Looking at the Odu, “Irente gbe” cast for today’s Ose Ifa, it is revealed that sometimes you sit down on the mat instead of kneeling down for supplication to Ifa. Just listen as follows:- Àyàn Awo Oníjan lódífá fún OníjanNíjó ...
Read More »
Ọmọ Oòduà Naija Gist | News From Nigeria | Entertainment gist Nigeria|Networking|News.. Visit for Nigeria breaking news , Nigerian Movies , Naija music , Jobs In Nigeria , Naija News , Nollywood, Gist and more