Omo ikò ti egbé olórin ìgbàlódé tí a mò sí Mavin, Reekado Banks ti gba okùnrin a gba àmì èye ní àlejò ní ilé rè, àwon méjèjì pín fídíò náà sí orí èro ayélujára. E wo àwòrán won ní ìsàlè.
Read More »Fact of the Century !
‘We must endeavor to study Ifa and start quoting Ifa instead of quoting Shakespeare’ – Omo Oba
Read More »Arákùnrin kan ni ó fi ìtò ara rè wè látàrí àpòjù ìmukúmu.
Arákùnrin kan ni ó fi ìtò ara rè wè látàrí àpòjù ìmukúmu. Arákùnrin kan ni a rí ní Ayobo, agbègbè kan ní ìpínlè Èkó tí ó n fi ìtò ara rè wè tí ó rò wípé omi ni látàrí ìmukúmu ...
Read More »Ayé Kareem ti yí padà di òtun láti ìgbà tí ó ti ya àwòrán Ààre Macron- Alákoso rè ló so béè.
Óríre míràn ti to omo kékeré, omo odún mókànlá tí a mò sí Kareem Waris Olamilekan tí olórun fún ní èbùn kí ó ma ta nkan, ó ti ya ààre ilè Faransé tí a mò sí Ààre Emmanuel Macron, nígbà ...
Read More »What The Abrahamic apologists want us to believe
Telling our stories begins from looking into the doings of our forebears and excavating the knowledge database resulting from the cultural practices of our ancestors. For so long, we have heard about who we really are from a people who ...
Read More »‘We Don’t Worship Idols Because There Is One God’ – Ooni Ile Ife
Ooni of Ife, Oba Ogunwusi Adeyeye Enitan has said that Ife sons and daughters are not worshipping idols, by celebrating Olojo festival yearly. He said there is one God, adding that people irrespective of their religions call upon him in ...
Read More »Ife Mefa: Ife ni orisun awa eda—Ife is the cradle of humanity!
Olu Igbo is just a revisionist. An attention seeker. He must know that divide and conquer tactics are are no longer fashionable. He should refrain from his unsubstantiated rhetorics. Ife ni orisun awa eda—Ife is the cradle of humanity Knowledge ...
Read More »Ifá – A Computer Programmer’s perspective
Ifá – A Computer Programmer’s perspective… For some of us who earn our daily bread from programming computers, making the connection between Ifá binary notation and programming is a no brainer. We programmers write codes/instructions (incantations) on the cpu – ...
Read More »Photos: Meet the New Aare Agbefaga of Oworonsoki Kingdom
Installation of Oloye Babalorisa Rudolph Eastman from Trinidad and Tobago as “Aare Agbefaga of Oworonsoki Kingdom” at the Palace of Araba of Oworonsoki Kingdom, Lagos on 4th September 2018 with Yeye Araba Banke Agboola, Oloye Dada Ifatoba, Erinmi of Oworonsoki ...
Read More »Ìròyìn Òrofó ní orílẹ̀ èdè Nàìjíríà.
1 Ààrẹ Buhari yóò dé lónìí láti orílẹ̀ èdè China. 2 Ọ̀jọ̀gbọ́n Ọ̀ṣínbàjò gba àlejò àwọn ọmọ orílẹ̀ èdè Nàìjíríà tí wọn gbé igbá orókè nínú ìdíje ìmọ̀ ẹ̀rọ ìgbàlódé. 3 Àwọn oníròyìn ń fi ìròyìn burúkú bá ìjọba Buhari ...
Read More »