Kí á dijú ká se bí eni tí ó kú kí á wo eni tí yó se ìdárò eni Ká fi esè ko gbàù kí á wo eni tí yó seni pèlé Ayé laó ti mo eni tí ó ń ...
Read More »Grace Oyelude, obìnrin àkókó tí Ó kókó gba àmì èye omidan arewà ní orílè èdè Nìjíríà.
Grace Oyelude, obìnrin àkókó tí Ó kókó gba àmì èye omidan arewà ní orílè èdè Nìjíríà. Ìyáawa Grace Atinuke, tí won bí ní ojó kerìndínlógún osù beelu ní odún 1931, tí a mò sí eni tí ó kókó gba àmì ...
Read More »Awada Toni: Omo Ibadan
Yoruba Gelede Masquerade
Written by Babalawo Ogunleke Ifamuyiwa Located between the Weme River in the Republic of Benin (RPB) and the Ogun River in southwestern Nigeria, western Yoruba-speaking people (Ketu, Egbado, Ohori, and Anago) are renowned for an elaborate masked performance tradition known ...
Read More »Check out this Interesting Egungun Song !
“There are some things about songs, expecially traditional songs, they are not just songs but vital messages that you will need to sit and break down to understand them. Last week, i was interviewed and ask that how can our ...
Read More »Bon-Odori: Egungun Festival in Japan
Obon (お盆) or just Bon (盆) is a Japanese Buddhist custom to honor the spirits of one’s ancestors. This Buddhist-Confucian custom has evolved into a family reunion holiday during which people return to ancestral family places and visit and ...
Read More »Irú kí ni eléyìí báyìí, àfi kí olúwa olódùmarè .
Nìjíríà àfi kí olórun gbà wá lówó gbogbo hílàhílo tí ó ń selè yí, irú kí leléyìí báyìí . Eléyìí ló selè ní Oghara. arábìnrin kan ni ó ún gun òkadà lo tí ó sì gbé epo beetíròlù séyìn nígbà ...
Read More »Ojó mánigbàgbé ní ilé-èkó gíga Obafemi Awolowo university (OAU).
Ojó mánigbàgbé ní ilé-èkó gíga Obafemi Awolowo university (OAU). Ìsèlè burúkú gbáà ní Óní selè ní ojó kewàá osù keje odún 1999 ní ilé-èkó gíga ifáfitì Obafemi Awolowo university nígbà tí èmi oní inú ire sì gba ibè lo. Afrika ...
Read More »AJE NIMO FẸẸ!
. AJE NIMO FẸẸ! Ohun aje f’oju miri ẹnu o le sọ; Oju miri to lori ọrọ aje; Owo(business) f’ẹgbin rẹmi lara; Ninu ẹgbin lọla fiṣe ile; Ọrọ kobakungbe inu iṣẹ-aje ni ngbe. Aje ogugu ni sọ; Onisọ iboji o; ...
Read More »Ogbón kò kúkú ní tán n’ílé ayé kí á wa lo sí òde òrun.
Ogbón kò kúkú ní tán n’ílé ayé kí á wa lo sí òde òrun. Arákùnrin kan ni ó so àwon táyà okò tí ó ti bàjé yí di tábìlì aláfé, okùnrin yí tí ó jé omo orílè èdè Nìjíríà. Kí ...
Read More »