A dúpẹ́ o Ikú ti di tiwa A dúpẹ́ o Àwọn èèyàn wa ò figi da mààlúù mọ́ AK 47 ni wọ́n ń lò A dúpẹ́ lọ́wọ́ Ọlọ́run Iṣẹ́ darandaran ti di iṣẹ́ dánràndáràn Èdùmàrè a dúpẹ́ o Ẹ dúró ...
Read More »Àbíkéyìn gbajúgbajà olórin tí a mò sí D’banj ni a gbó wípé Ó kú sí omi ní àná.
omokùnrin gbajúgbajà olórin tí a mò sí D’banj tí orúko omo náà ń jé Daniel ni a gbó wípé Ó kú sí omi ní àná tí a mò sí ojó kerìnlélógún osù kerin odún yii. Kí olúwa kí ó bá ...
Read More »Rántí òla
Ohun tí a se lónìí Ìtàn ni b’ódòla Lisabi Agbongbo Àkàlà Fi ìwà akin gba gbogbo Ègbá kalè L’óko erú Olóòyó Ògèdèngbé ń be nínú ìwé ìtàn ìjeshà Asíwájú rere ní se Moremi obìnrinkùnrin n’ífè ńkó, a kò le gbàgbé ...
Read More »Ọ̀YÀYÀ (CHEERFULNESS)
Èro àlọ, Ẹ wá gbọ́, èrò àbọ̀, Ẹ wá tẹ́tí sími Oògùn ọlá tí mo ṣẹ̀ṣẹ̀ rí ní mo fẹ́ wí f’áyé Oògùn ọrọ̀ tí mo ṣẹ̀ṣẹ̀ gbà ní mo fẹ́ ròyìn Àtọjọ́ mo ti dáyé, Àtọjọ́ mo ti ń ...
Read More »Oonirisa ni Ilu Oyibo: Abike jagaban, Esabod..
Ìgbà èdá
Ìgbà kò lo bí òréré Ayé kò lo bí òpá ìbon, Ìgbà kan ńlo Ìgbà kan ńbo Kí elédùmarè jé kí á n’ígbà tó dára n’ílé ayé wa Ìgbà kan ni ogún náírà yí níyì púpò Sùgbón nísìnín Ó ti ...
Read More »Ahmed Musa ti mu Nìjíríà rérìn-ín ayò léèkan sí.
Gégé bí a ti mò wípé eré bóòlù ife àgbáyé ńlo lówó. Ahmed Musa tí Ó jé òkan Lára àwon omo agbábòòlú Nìjíríà ti gbá bóòlù méjì òtòtò wo ilé àwon alátakò won tí a mò sí ikò Iceland.
Read More »Photo news: Ifa is reliable !
Ifa is Light !
Read More »Òrìsà tí ń darí aféfé
Oya òpèré, Ekùn oko asè’ké Oya má bá mi jà Mi ò l’ówó aféfé ńlé Èmi ò rí eni tí yó ràgàn, ràgàn bí Oya ní òde ìpo Kò séni tí ó ràgàn ràgàn bí Oya lótù ifé Oya lo ...
Read More »Meet Paula Cristina Gomez – Cultural Ambassador, Alaafin Oyo
Àlàáfíà, Some days ago, The Ooni took his first official trip to Brazil, to connect with his subjects. According to a facebooker: ‘I got information for a very reliable source that the white, she-Devil called Paula Cristina Gomez, the self ...
Read More »