Ọbàtálá ọbátárìsàỌba pátápátá tí ń bá wọn gbóde iránjéỌba nílé Ifọ́nÒ sùn nínú àlàÒ jí nínú àlàÒ tí inú àlà dìdeÒrìṣà wun mi ní budoIbi Ire l’òrìsá kalẹ Akú òsè Obàtálá O kettle drum
Read More »
ayangalu Comments Off on Oríkì Obàtálá
Ọbàtálá ọbátárìsàỌba pátápátá tí ń bá wọn gbóde iránjéỌba nílé Ifọ́nÒ sùn nínú àlàÒ jí nínú àlàÒ tí inú àlà dìdeÒrìṣà wun mi ní budoIbi Ire l’òrìsá kalẹ Akú òsè Obàtálá O kettle drum
Read More »ayangalu Comments Off on Ẹ ẹ̀ ṣi nọ́ńbà mú l’Ọyọ, gbogbo owó yín tí mo bá ná, ẹ ó rí n tí mo fi se – Seyi Makinde
Ẹ ẹ̀ ṣi nọ́ńbà mú l’Ọyọ, gbogbo owó yín tí mo bá ná, ẹ ó rí n tí mo fi se…..Seyi Makinde Fẹ́mi Akínṣọlá Àwọn àgbà ní bí Ọlọ́run bá sẹ̀rí ì rẹ,jẹ́ kí èèyàn náà ó sẹ̀rí ì rẹ ...
Read More »ayangalu Comments Off on Ọmọọba mẹwàá ló du òyè pẹ̀lú mi – Aláàfin Ò̩yó̩
Ọmọọba mẹwàá ló du òyè pẹ̀lú Adeyẹmi, tó sì já mọ lọ́wọ́. Fẹ́mi Akínṣọlá Ọlayiwọla Adeyẹmi Kẹta, ti pé ẹni ọdún mọ́kànlélọ́gọ́rín lókè eèpẹ̀ bẹ́ẹ́ ló ti lo ọdún méjìdínláàdọ́ta lórí ìtẹ́ àwọn baba ńlá rẹ̀. Òjò ti ń pa ...
Read More »ayangalu Comments Off on llé iṣẹ́ ọ̀lọ́pàá ,ẹ dá ìgbaniwọlé tí ẹ gùnlé dúró… Àṣẹ ilé ẹjọ́
llé iṣẹ́ ọ̀lọ́pàá ,ẹ dá ìgbaniwọlé tí ẹ gùnlé dúró… Àṣẹ ilé ẹjọ́ Fẹ́mi Akínṣọlá Ṣé àwọn àgbà ní ilé tí a fi itọ́ mọ, ìrì ni yóò wo. Ọbẹ̀ tí a fi èké pilẹ̀ ẹ rẹ̀, í í ru ...
Read More »ayangalu Comments Off on Yoruba does not exist in Ifa ― Elebuibon
By Shina Abubakar – Osogbo A renown traditionalist and the Araba of Osogbo, Chief Ifayemi Elebuibon said prior to contact with the Hausa/Fulani, the race is known as the people of Ife, saying it is unfortunate that the people failed ...
Read More »scully009 Comments Off on Naira (NGN) Trading pair becomes the first FIAT on Binance
Binance listed the 1st ever fiat trading pair, and it’s not the US dollar. Beginning today, Nigerian users will have a way to get Bitcoin, Binance Coin (BNB), and Binance’s stablecoin BUSD with Naira. Buy Bitcoins In Nigeria Blog Reports ...
Read More »BalogunAdesina Comments Off on Revisiting the win-win-win-win outcome in Syria
this analysis was written for the Unz Review] In his recent article “The Road to Damascus: How the Syria War Was Won” Pepe Escobar summarized the outcome of the war in Syria in the following way: “It’s a quadruple win. The ...
Read More »ayangalu Comments Off on Àsírí Òkété
ÒKÉTÉ.___Òkété jẹ́ ọ̀kan nínú ẹranko abàmì tó lágbára púpọ̀. A sì máa gbé nínú ihò. ELÉDÙMARÈ fún-un ní àṣẹ púpọ̀.Òkété kìí fi ọwọ́ tàbí ẹṣẹ̀ gbẹ́ ihò, ÌRÙ ni òkété maá n fií gbẹ́ ihò, fún ìdí èyí, ẹ ò ...
Read More »ayangalu Comments Off on Ṣé Ìwọ mọ pé gbogbo agboolé nílùú Igbóọrà ní wọn ń bí ìbejì ?
Ṣé Ìwọ mọ pé gbogbo agboolé nílùú Igbóọrà ní wọn ń bí ìbejì ? Fẹ́mi Akínṣọlá Ṣé kò sí ìlú tí kò ní àdámọ́ ọ ti ẹ̀. Bẹ́ẹ̀ gẹ́lẹ́ lọ̀rọ̀ rí nílùú Igbóọrà .Igbóọrà jẹ́ ìlú kan tó kalẹ̀ si ...
Read More »ayangalu Comments Off on Iṣẹ́ ìránṣẹ́ kò sí fún ìmẹ́lẹ́ èèyàn – Tunde Bakare
Fẹ́mi Akínṣọlá Ayé ló bàjẹ́ tí ọmọ olè ń dájọ; oníkálukú mọ ẹ̀tọ́ tó yẹ́’.Olùṣọ́ àgùtàn Tunde Bakare ṣàlàyé bí ìdámẹ́wàá ṣe bẹ̀rẹ̀ ninu Bíbélì àti pé kò si ẹni tí wọ́n gbé ìbọn tì pé dandan ni kó san ...
Read More »
Ọmọ Oòduà Naija Gist | News From Nigeria | Entertainment gist Nigeria|Networking|News.. Visit for Nigeria breaking news , Nigerian Movies , Naija music , Jobs In Nigeria , Naija News , Nollywood, Gist and more