Artist: Moyo Okediji Title: Awo, Èṣù and Ọ̀rẹ̀rẹ̀ Medium: Terracotta on canvas.
Read More »
ayangalu Comments Off on Photo of the Week: Awo, Èṣù and Ọ̀rẹ̀rẹ̀
Artist: Moyo Okediji Title: Awo, Èṣù and Ọ̀rẹ̀rẹ̀ Medium: Terracotta on canvas.
Read More »Awoyemi Bamimore Comments Off on A kú osù tuntun oo.
Owó✋lá fi n sisé owó Esè la fí ñ rìnnà Olà Àtowó àtesè ki Elédùmarè má gba ìkankan nínú rè lówó wa, ká lè fi rí nñkan Ajé kó jo… Asáré pajé Arìngbèrè polà Òhun ewà ní wón jó n ...
Read More »Bitcoin has finally surmounted the maximum psychological barrier of, passing ₦3,640,000 ($10,000) and showing no signs of stopping. Carrying out a week of consolidating at all-time high levels around ₦2,912,000 ($8,000), Bitcoin found the strength to go up powerfully during ...
Read More »Awoyemi Bamimore Comments Off on Arábìnrin yí ni ó wàású fún awakò yí, tí ó sì yi padà sí kìrìsìténì láti mùsúlùmí.
Arábìnrin tí ó jé ò n lò èro ayárabíàsá (Twitter) tí a mo orúko rè sí Caramella Mou ní won fi èsùn kàn ní órí èro ayárabíàsá látàrí wípé ó wàású fún arákùnrin awakò kan tí ó jé mùsùlùmí ...
Read More »Awoyemi Bamimore Comments Off on “Èmi ni mo ni é” Adesua Etomi ni ó sobéè fún Banky W nígbà tí ó pín àwòrán ìgbéyàwó won.
Àrídájú ti wà báyìí wípé Adesua Etomi àti Banky W ti di tokotayà, gbajúgbajà òsèré bìnrin ni ó sèsè pín àwòrán won yí tí ó sì so irú ìfé tí ó ní fun, nse ni ó dàbí eni wípé ...
Read More »Awoyemi Bamimore Comments Off on Àwòrán kí ó tó di ojó ìgbéyàwó ti arábìnrin tí ó tóbi àti oko aràrá.
Nígbà tí mo rí àwòrán yí ní orí èro ayélujára , mo kókó dúró ná mo wá bi ara mi ní ìbéèrè wípé kíni obìnrin fé nínú ìgbéyàwó tàbí lára okùnrin ? Léyìn òpò ìrònú àti òpò ìrírí ...
Read More »Awoyemi Bamimore Comments Off on E wo aso Ebuka níbi ìgbéyàwó alárédè ti Banky W àti ìyàwó rè, Adesua Etomi.
Òpò ni ara ti n yá tí won sì ti fi ojú s’ónà láti wo aso tí Ebuka ma wò ní òtè yí báwo ni ó ti è se ma rí nínú rè ni ìbéèrè àwon ènìyàn, bí ó tilè ...
Read More »Awoyemi Bamimore Comments Off on Àwòrán ìsìnkú Akékòó jáde ti ilé èkó gíga Nnamdi Azkiwe (UNIZIK) tí ó kú ní òsè mélòó séyìn.
Olóògbé Arábìnrin Amaka Ezeokoli tí ó kú ní òsè mélòó séyìn léyìn àìsàn péréte , se ni won ti sin-ín ní ojó Àbáméta (Saturday) ní ìlú tí won bi sí ní Ezioko ní ìjoba ìbílè Gúúsù ti Orumba tí ó ...
Read More »” O le wá fi enu ko ìyàwó lénu báyìí” ni ó ma n dùn jù nínú ìgbéyàwó, tí kò bá rí béè Banky W àti Adesua kò bá má se tó báyìí, won ti fi enu ko ara lénu ...
Read More »Awoyemi Bamimore Comments Off on Ìsìnkú àwon tí won kú níbi ìjàmbá okò tí ó selè láìpé ní ìpínlè Imo.
Gégé bí Holychidi Ojlkorie, ìgbákejì olùgba oko àti aya n’ímòràn ti ìjoba ní ìpínlè Imo télè, òpò ènìyàn bí ogbòn ni won kú níbi ìjàmbá burúkú tí ó selè láìpé láàrin glokò epo petiróòlù àti okò èrò elérò méjìdínlógún (18) ...
Read More »
Ọmọ Oòduà Naija Gist | News From Nigeria | Entertainment gist Nigeria|Networking|News.. Visit for Nigeria breaking news , Nigerian Movies , Naija music , Jobs In Nigeria , Naija News , Nollywood, Gist and more