Gómìnà ìjoba ìpínlè River, Nyesom Wike ní òwúrò yí dá Konmisôna isé dúró ní ìpínlè rè tí orúko rè ńjé Bathuel Harrison (àwòrán eni tí ó wo jákèètì). Nínú òrò tí olùrànlówó pàtàkì rè so lórí ìtànná ohun Ìgbéròyìn jáde ...
Read More »
ayangalu Comments Off on Gómìnà Nyesom Wike dá òkan lára àwon Konmisôna rè dúró.
Gómìnà ìjoba ìpínlè River, Nyesom Wike ní òwúrò yí dá Konmisôna isé dúró ní ìpínlè rè tí orúko rè ńjé Bathuel Harrison (àwòrán eni tí ó wo jákèètì). Nínú òrò tí olùrànlówó pàtàkì rè so lórí ìtànná ohun Ìgbéròyìn jáde ...
Read More »ayangalu Comments Off on Díè nínú ìsesí láti òdò Dino Melaye lórí ìròyìn èrò rè tí a se ìrántí láti ìgbìmò asòfin àgbà.
Ní àná, ìgbìmò tí ó ń darí ètò ìdìbò (INEC) gba àpò méfà tí ó kún fún ìbowólù àwon tí ó tó láti dìbò ní agbègbè Eokun ìwò oòrùn ní ilè Kogi, tí ó ń bèèrè fún ìrántí Dino Maleye ...
Read More »ayangalu Comments Off on Ipò Burúkú Ti Ilé-ìwòsàn Ńlá Ní Warri Ní Ìjoba Ìpínlè Delta Wà.
Èyí ni ìròyìn ipò tí ilé-ìwòsàn ńlá wà ní warri ní ìjoba ìpínlè Delta wà lówólówó . Àwòrán na jé pínpín sí orí èro ayélujàra (facebook) English Version Continue after the page break
Read More »ayangalu Comments Off on Ilé Tí Won Ń Kó Lówó Wó Ní Ilorin.
Èrù ti ń ba àwon òpòlopò ènìyàn bóyá àwon ènìyàn kú sí inú ilé tí won ń kó lówó ní òpópónà Stella, Tanke ,Ilorin ,ní ìjoba ìpínlè Kwara tí ó wó ní òsán yí. English version Continue after the page ...
Read More »BalogunAdesina Comments Off on Kalibr cruise missiles strikes on ISIS targets in Syria by the Russian Navy
On June 23, Russian Ministry of Defense reported missile strikes against the IS (Islamic State) in Syria The official statement in Russian. The missiles were launched from Russian Navy frigates, the Admiral Essen and the Admiral Grigorovich, as well as a submarine, the Krasnodar, ...
Read More »Lolade Comments Off on ‘Smart Thief’ Caught on Cam stealing Phone – Watch
Watch as this big berried thief was nabbed steeling phone. The guy s a caring thief.. hehe… He even gave him stapler. He also alerted him before leaving as a gentleman. Omg!!! People are ‘amazing’
Read More »BalogunAdesina Comments Off on The latest escalation in Syria – what is really going on?
This article was written for the Unz Review. By now most of you have heard the latest bad news of out Syria: on June 18th a US F/A-18E Super Hornet (1999) used a AIM-120 AMRAAM (1991) to shoot down a ...
Read More »ayangalu Comments Off on Àwòrán Obanikoro àti Oluremi Tinubu àti àwon omo egbé APC tó kùn ní ìlú èkó.
Ní ìsàlè yìí ni àwòrán sineto Obanikoro àti sineto Oluremi Tinubu àti àwon tó kùn. Ní ìpàdé kejilélógún (22nd) ní ibi ìpàdé àwon sinetò ní agbègbè èkó …. English Version after the page break
Read More »ayangalu Comments Off on Inú àwon olólùfé 2baba dùn púpò nígbà tí won rí olólùfé won ní Glomega music tour tí ó wáyé ní Victoria Island, ní ìlú èkó.
Gbajúgbajà olórin 2baba jé òkan lára àwon tí ó korin ní Glomega tour ní VI ní ìlú èkó. Ó tún wú àwon ònwòran lórí nígbà tí ó f’akoyo lórí ìtàgé. Ewo àwòrán bí ó se Ń dá won lárayá n’ísàlè.. ...
Read More »ayangalu Comments Off on Àwon olólùfé Biodun Okeowo wí fun pé kí ó pa àwòrán rè tí ó wo aso tí ó fun ré.
Òsèré Biodun Okeowo tí a mò sí Omobutty, ni àwon olólùfé rè ń sòrò sí látàrí àwòrán tí ó pín ní bi tí ó ti wo aso tí ó gbé èyà ara rè jáde… Continue after the page break for ...
Read More »
Ọmọ Oòduà Naija Gist | News From Nigeria | Entertainment gist Nigeria|Networking|News.. Visit for Nigeria breaking news , Nigerian Movies , Naija music , Jobs In Nigeria , Naija News , Nollywood, Gist and more