Gégé bí ìròyìn se so, Gómìnà ìpínlè Kogi: Yahaya Bello ri èro amúnáwà tí agbára rè tó Egbèédógún (300KVA) ní òpópónà kan ní Lokoja gégé bí isé rè àkókó léyìn tí ó ti lo odún kan àti ààbò lórí ipò. ...
Read More »Owó te olùsó àgùntàn(pastor) èké kan nígbà tí ó ń gbìyànjú láti ri ohun tí a kò mò sí ilé onílé.
Olùsó àgùntàn èké kan tí a mò sí Osinachi Christopher láti ìpínlè Abia ni won fi s’èsín léyìn ìgbà tí owó ti tèé nígbà tí ó ń gbìyànjú à ti ri ohun tí a kò mò sí ilé onílé ní ...
Read More »Check out Top 5 Reasons Why Bitcoins is here to stay.
An important issue hindering Bitcoin is uncertainty about its future. The debate is finished whether Bitcoin would have been a successful long haul innovation or fizzle out like so many prior innovations. It’s possible to create a relatively accurate prediction ...
Read More »Ilé ejó gíga jù dá asòfin ìpínlè Taraba dúró, tí orúko rè ńjé Sani Danladi
Won pàse fun kí ó dá owó osù àti àláwánsì tí ó gbà. Ilé ejó gíga jù ti pàse fún asòfin tí ó ń sojú ilé asòfin àgbà àríwá ti ìpínlè Taraba sani Abubakar Danladi láti fi ipò náà sílè ...
Read More »Àwon Agbófinró ìpínlè Èkó so ònà tuntun tí àwon gbómogbómo ńgbà jínigbe.
Àwon Agbófinró ìpínlè Èkó so ònà tuntun míràn tí àwon gbómogbómo ńgbà jínigbe. Ní ìsàlè ni òrò tí agbenuso àwon Agbófinró ìpínlè Èkó, SP Dolapo Badmos so. “E jò ó tí enikéni bá fi káàdì ìpè ráńsé sí yín tí ...
Read More »Video: Nigerian mathematician Builds Flying F-35D prototype (Flying Drone)
Time to invest heavily in this man.
Read More »Àwon ológun yín ìbon lu omokùnrin odún márùn-ún ní Kaduna nígbà tí won ń ké ìrora won ní rowérosè ..
Gégé bí omo oòduà rere se so, omokùnrin odún márùn-ún tí orúko rè ńjé Hussein Mustapha ni àwon ológun yin ìbon lu nígbà tí won ń ké ìrora (rally) ní Kaduna láti fi àmì sí Qusday ní àgbáyé láti gba ...
Read More »Alaafin Of Oyo Declares fake Ifa Priests Wanted, Sues Them For Giving Oyinbo Titles
PUBLIC NOTICE UNSCRUPLOUS ACTIVITIES OF SOME IFA PRIESTS IN OYO Recent events in Oyo and other parts of the world concerning the activities of some Ifa priests from IJO IFA ADIMULA TEMPLE, BARA in Oyo town, wherein unsuspecting foreigners who ...
Read More »Gómìnà Nyesom Wike dá òkan lára àwon Konmisôna rè dúró.
Gómìnà ìjoba ìpínlè River, Nyesom Wike ní òwúrò yí dá Konmisôna isé dúró ní ìpínlè rè tí orúko rè ńjé Bathuel Harrison (àwòrán eni tí ó wo jákèètì). Nínú òrò tí olùrànlówó pàtàkì rè so lórí ìtànná ohun Ìgbéròyìn jáde ...
Read More »Díè nínú ìsesí láti òdò Dino Melaye lórí ìròyìn èrò rè tí a se ìrántí láti ìgbìmò asòfin àgbà.
Ní àná, ìgbìmò tí ó ń darí ètò ìdìbò (INEC) gba àpò méfà tí ó kún fún ìbowólù àwon tí ó tó láti dìbò ní agbègbè Eokun ìwò oòrùn ní ilè Kogi, tí ó ń bèèrè fún ìrántí Dino Maleye ...
Read More »