Oloye Yemi Elebuibon, The Araba of Osogbo, tells us about the Yoruba days of the week and their origin. Tunde Kelani is known for his great movies such as Saworo Ide, Agogo Eewo, Oleku, Ti Oluwa nile, etc. Ọjọ́ Àìkú ...
Read More »Ibeere Toni
Egbo eyin o ogbon,…nje oda ki Iyawo ile o mo ko orun fun okore ? ….tabi ki oko naa o ko fun Iyawo re?……. Iru nkan wonyi se o ma ndin Ife Ku ni abi oma tubo mufe gbile si???????????
Read More »Oko mi ati iya re loba aye mi je
Akole oke yi lo se apejuwe oro arabinrin kan , eyi to fi esun kan iya oko re wipe o gba arisiki oun fun omo (oko re) Nigbati obinrin yi so oro , emi bi leere wipe SE OKO SAA ...
Read More »Iwure Owuro Ipari Osu
E MAA WI TELE MI : ….. *Airije-airimu nile aye mi ti dopin. *Ibanuje ninu aye mi ti dopin. *Ijakule ninu aye mi ti dopin. *Ise mi ko ni dojuru *Ogun aye ko ni borii mi. *Oju owo ko ni ...
Read More »Ritual painting By Ifa professor Moyo
ỌBALÚAYÉ ritual, painting and photography by Prof. Moyo Okediji See full painting after the page break bellow.
Read More »Photos: Man electrocuted on PHCN poll in Kaduna (Pics)
The young man was electrocuted this afternoon in Kaduna state opposite station market. See more photos after the page break…
Read More »Video – Davido & His Crew Beat Up One Of His Fans In London
Well – Guess what Davido can do!? He can sing and also fight, watch the video of him trashing up a fan in London
Read More »Fi ere si temi Eledumare
Ojulu! ojo nan re bi anan sugbon o ti pe odun kan bayi Eledua modupe, ibi ti ore nan de duro maje ko taku sibe o, fi ere si temi Eledumare, MAJE KIN KAABAMO BO TI WU KORI, orewa toripe ...
Read More »Orewa Abi Iwonan Ti Gbagbe Ile !
Orewa abi iwonan ti gbagbe ile, toripe eniyan to so ile nu ti so apo ‘ya ko, ajo ko dabi ile lo d’ifa fun agiliti to pada wa tun ile-baba re se, se ki se pe o ti gbagbe orirun ...
Read More »Oba Erediauwa Ti Waja
Ojulu ooooo! iku ti pa abiri abiri ti rorun alakeji oooo! iku ti pa okan lara awon omo ODUDUWA Oba-Benin, gbogbo eyin ojulowo omoYORUBAatata e ku araferaku eni re OBA-EREDIAUWA ti ile-benin. bo ba de orun ko se orun re. ...
Read More »